GUARD YOUR COMPANY

GUARD YOUR COMPANY

THE SEED

“…bad company corrupts good character.” — 1 Corinthians 15:33 (NIV)

Friendships and associations shape our faith walk more than we realize. Bad company can weaken spiritual convictions and lure believers into compromise. That’s why Scripture warns against being unequally yoked with unbelievers. While we must show love to everyone, wisdom is needed to discern who has influence over our lives. Spirit-led companionship builds, but ungodly influence gradually pulls down. Choose your inner circle carefully. Let those closest to you be people who strengthen your faith, not drain it.

Reflection: Who you walk with can shape where you end up.

 

BIBLE READING: 2 Corinthians 6:14–18

PRAYER: Lord, give me wisdom to choose my company wisely and courage to stand for You at all times. Amen.

 

ṢỌ́ ẸGBẸ́ RẸ

IRUGBIN NAA

“Egbẹ́ búburú a máa ba ìwà rere jẹ́.” – 1 Kọ́ríńtì 15:33

Ọ̀rẹ́ àti awon alabarin máa n ní ipa lórí ìrìn ìgbàgbọ́ wa ju bí a ti ṣe rò lọ. Ẹgbẹ́ búburú lè sọ ìgbàgbọ́ ẹ̀mí di aláìlera, kí ó sì fa àwọn onígbàgbọ́ sínú irewesi. Ìdí nìyẹn tí Ìwé Mímọ́ fi kìlọ̀ fún wa pé a kò gbọ́dọ̀ fi àìdọ́gba dàpọ̀ pẹ̀lú àwọn aláìgbàgbọ́. Bó tilẹ̀ jẹ́ pé a gbọ́dọ̀ fi ìfẹ́ hàn sí gbogbo ènìyàn, a nílò ọgbọ́n láti mọ ẹni tí ó ní agbára lórí ìgbésí ayé wa. Ìbárẹ́ ti a tí ẹ̀mí darí maa n ngbéniró, ṣùgbọ́n ibasepo egbe aye a máa wó ni lulẹ̀ díẹ̀díẹ̀. Yan awon ore re pẹ̀lú ìṣọ́ra. Jẹ́ kí àwọn tí ó sún mọ́ ọ jẹ́ àwọn ènìyàn tí ó ń fún ìgbàgbọ́ rẹ lágbára, kì í ṣe kí wón mú idibàjẹ́ wá.

Asaro: Ẹni tí o bá rìn lè sọ ibi tí o ma dé.

 

BIBELI KIKA: 2 Kọ́ríńtì 6:14-18

ADURA: Olúwa, fún mi ní ọgbọ́n láti yan ẹgbẹ́ mi pẹ̀lú ọgbọ́n àti ìgboyà láti dúró fún ọ nígbà gbogbo. Amin

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *