SIGNS AND WONDERS  THE SEED 

 

SIGNS AND WONDERS  THE SEED 

MAY  

2 MON 2022 

“How great are His signs! and how mighty are His wonders! His kingdom is an everlasting  kingdom, and His dominion is from generation to generation.” Daniel 4:3 As Christians, we are made for signs and wonders to the world. God made it so to show  the world that He is alive and He is the supreme God. Signs and wonders are real and durable.  To be the people of signs and wonders, we should not have assumptions about God.  We must consciously invite Jesus in those issues that we expect signs and wonders.  Don’t assume that God knows – John 2:3-4. Don’t assume that God has power, seek for it – Matthew 7:7. Don’t assume the presence of God, we must call for it – Jeremiah 33:3. Recognising  God’s presence is vital for signs and wonders. We must never stop witnessing through the  preaching of the Word and our transformed lives, but we must also be conscious of the Holy  Spirit’s power to manifest Signs and Wonders for more empowered evangelism. As proven time  and time again throughout history, when people see signs and wonders, along with the  proclamation of the Word, multitude upon multitude will be swept into the Kingdom. Dearly beloved, God is looking for those who will trust Him beyond their own senses,  education, intellectual understanding, and experience (Prov 3:5-8), to manifest His signs and  wonders. Praise the Lord, Hallelujah! God bless you richly in Jesus mighty name. PRAYER 

O Lord, let your signs and miracles be permanent in my life in Jesus name Amen. BIBLE READINGS: John 2: 1-11 

ISE AMI ATI IYANU 

IRUGBIN NAA 

“Ami re ti tobi to! Agbara ise iyanu re ti po to! Ijoba ainipekun ni ijoba re, ati agbara ijoba  re, ati irandiran ni.” Danieli 4:3 

Gege bi onigbagbo, a da wa si aye fun ise ami ati iyanu. Oluwa mu ki o ri bee ki o le fi  han aye wipe oun wa laaye ati wipe oun ni Olorun ti o ga julo. Ise ami ati iyanu wa nitooto. Ki a  le je eni ise ami ati iyanu, a ko gbodo se tabi sugbon nipa Olorun. 

A gbodo fi tokantokan pe Jesu lori awon ohun ti a n reti ise ami ati iyanu lelori. Mase ro o  ni okan re wipe Olorun mo. Johannu 2:3-4. Mase wipe sebi Olorun ni agbara, se awari re-Matteu  7:7: mase ro o lokan wipe Olorun wa laarin yin, a gbodo beere fun un. Jere 33:3 Iwa laaye Olorun ni ibi kan se Pataki fun ise ami ati iyanu. A ko gbodo dekun ati maa jeri nipa  wiwaasu oro naa ati igbe aye wa ti o yi pada sugbon a gbodo mo wipe agbara emi mimo ni n fi  ise ami ati iyanu han fun ise ihinrere ti o ni agbara. Gege bi a ti ri daju ni opo igba sehin, nigba ti  awon eniyan ba ri ise ami ati iyanu ni asiko ti a ba kede ihinrere, opolopo okan ni a maa n jere si  ijoba Olorun. Olufe owon, Olorun n fe awon ti yio gbeke le e ju ogbon ori ti won, eko won, oye  ori ati iriri won (Owe 3:5-8) ki won le fi ise ami ati iyanu re han. E yin Oluwa logo, Halleluyah!  Oluwa yio bukun yin lopolopo ni Oruko Jesu. 

ADURA 

Oluwa, je ki ami ati iyanu re ki o je ajemonu fun mi l’oruko Jesu. Amin 

BIBELI KIKA: Johanu 2: 1-11 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *