DIVINE HEALTH THE SEED 

 

DIVINE HEALTH THE SEED 

MAY  

3 TUE 2022 

“For they are life unto those that find them, and health to all their flesh.” Proverbs 4:22 The Word of God is filled with power to produce life and health in the believer in Christ  Jesus. Nonetheless, before one can receive the life and health in the scriptures, one must first  pay attention to the Word: to listen with rapt attention.  

Secondly, study the Word and see mental pictures of it. Finally, keeping it in your heart  or make a conscious effort to memorise or meditate the scriptures.  

When these three steps are concluded the power in the Word is released to produce life  and healing in you. The life and health the Word produces are more than what any medicine  can provide.  

The wish of every believer in Christ Jesus should be a strong desire to pursue divine  health.  

Dear beloved, the world is sick and children of God must have the right connection in  order to walk in dominion over sicknesses, diseases and death and that connection is Jesus  Christ. On a daily basis, learn to appropriate Him. Remember that He is the incarnate Word.  

Let the river of life flow in you and through you continually; anywhere there is a flow,  there are deposits and part of that deposit is health, wealth, wisdom and life. PRAYER 

Lord Jesus, grant your divine health to the sick in Jesus Name Amen. 

BIBLE READINGS: James 5: 10-16 

ILERA ATOKEWA 

IRUGBIN NAA 

Nitori iye ni won n se fun awon ti o wa won ri, ati imularada si gbogbo eran ara won. Owe  4:22 

Oro Olorun kun fun agbara lati fun awon ti o gbagbo ninu Kristi Jesu ni iye ati ilera.  Sugbon, ki a to le ri iye ati ilera ti inu iwe mimo, a gbodo koko fiyesi oro naa: ki a feti sile  daradara. 

Ekeji, ko eko oro naa ki o si se afiyesi itumo re. Ni ipari, pa a mo ninu okan re tabi ki o  gbiyanju lati mo o sori ki o si maa se asaro ninu iwe mimo. 

Lehin awon ipele meta yii, agbara ti n be ninu oro naa yio fun o ni iye ati ilera. Iye ati ilera ti oro  yii n fun ni, o poju ohun ti oogun oyinbo le fun ni lo. 

Ohun ti o ye ki o wu gbogbo onigbagbo ninu Jesu ni ife lati lepa ilera pipe atokewa. Olufe owon, aisan po ni aye, awon omo Olorun si gbodo ni ibasepo pelu Jesu Kristi ki won baa  le ni isegun lori aisan, aarun ati iku.  

Ko bi a tii npe e lojoojumo. Ranti wipe oun ni oro ti a so di ara. Je ki odo omi iye ki o maa  san ninu re ni igba de igba. Nibiti odo ba ti san, a maa ri ipa, lara eyi tii se ilera, oro, ogbon ati  iye. 

ADURA 

Jesu Oluwa, fi ilera atoke wa fun awon ti nse aare ni oruko Jesu. Amen 

BIBELI KIKA: Jakobu 5: 10-16 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *