AN EXPECTED END
THE SEED
MAY 22 SUN 2022
“For I know the thoughts that I think toward you, saith the LORD, thoughts of peace, and not of evil, to give you an expected end.” Jeremiah 29:11
The children of God can know the intention of God towards them: the intention is good, one of peace to give them an expected end. The question is what is your expectation as a child of God? Is your expectation in conformity with the scriptures?
If your expectation is in line with God’s word, then God will surely fulfill it. Since our God is a great God, let us have great expectations which are supported by the scriptures; and let us declare these scriptures continually and see how God will bring them to pass.
That’s where you’ll find your peace – when you know Him and believe Him, when you know that despite desperate or discouraging circumstances, the end to your challenges shall surely come and will be in accordance to your expectation(s). He will make all things right whether you can imagine it now or not.
Dear beloved, this security, this soundness, contentedness, completeness and unity with God is found only and uniquely in Christ. Praise the Lord, Hallelujah! God bless you richly in Jesus mighty name. Amen.
PRAYER
O Lord, do not allow my Godly expectations to fail before you in Jesus name Amen. BIBLE READINGS: Jeremiah 29: 8-14
IGBA IKEHIN
IRUGBIN NAA
“Nitori Emi mo iro ti mo ro si yin, li Oluwa wi, ani iro alaafia, ki si ise fun ibi, lati fun nyin ni igba ikehin ati ireti.” Jeremiah 29:11
Awon omo Olorun le mo erongba Olorun si won: ero Olorun dara, eyi ti o je ti alaafia lati fun won ni ikehin ti o dara. Ibere ni pe kini ireti re bi omo Olorun? Nje ireti re wa ni ibamu pelu oro inu iwe mimo?
Bi ireti re ba ri bakan naa pelu ti oro Olorun, o daju pe Olorun yio mu u se. Niwon igbati Olorun wa je Olorun ti o tobi, e je ki a ni ireti ti o tobi ti o si ni atilehin oro inu iwe mimo: ki a si ma a pe awon oro wonyi si ara wa, pelu idaniloju nigbagbogbo; ao si ri bi Olorun yio se mu won wa si imuse.
Nibiyi ni oo ri alaafia re – lehin igbati o ba Mo o ti o si gbaa gbo, ti o si mo pe labe akori ohunkohun ti o nla koja, opin yio de si awon wahala wonyi; won yio si wa ni ibamu pelu ireti re. Yio mu ohun gbogbo bo sipo yala o lero re tabi o o ni.
Olufe owon, aabo, ilera ti o peye, ifokanbale, asepe, ati isokan pelu Olorun awon nkan wonyi ni a le ri ninu Kristi. E yin Oluwa logo alleluia Oluwa yio bukun yin ni kikun ni oruko Jesu amin.
ADURA
Oluwa ma jeki ireti mi ki o ni ijakule ninu Re ni oruko Jesu Amin.
BIBELI KIKA: Jeremiah 29: 8-14