BE TRAINED

 

BE TRAINED

THE SEED 

“Seest thou a man diligent in his business? He shall stand before kings; He shall not stand  before mean men.” Proverbs 22:29.  

When you see someone that is good at what he or she does, it is most likely that the  person has an inherent ability, or he/she has been trained in it.  

A professional is defined as someone who displays high levels of expertise and  efficiency in their work, and it is inherent to say that someone addressed as a professional must  have undergone various trainings, for him or her to have attained such a height in his or her  career/profession. Whether in the spiritual or physical engagements, one needs to accept being  trained in what you do. Submit yourself to being tutored.  

The disciples were under the tutelage of Christ Jesus before they were later called the  Apostles. Training takes a lot of effort and dedication, but it helps you to acquire wisdom,  knowledge and understanding to become a master of your activities.  

Practice your songs, read, and memorise that Bible verse repeatedly, practice how to  evangelise, ask for and accept corrections, be trained in the work of the ministry, be trained in  counselling. Follow the instructions of the Holy Spirit, learn from God-inclined people and you  shall be empowered through receiving training. 

PRAYERS 

Lord, help me to maximise and utilise my training period effectively in Jesus name. Amen. BIBLE READINGS: Proverbs 4:1-13 

DÀBÍ ENITI O NÍ ẸKỌ 

IRÚGBÌN NÁÀ 

“Ìwo rí eniyan tí o nfi aisemele e ìe rẹ? òun o duro n’iwaju awọn ọba; oun kí yíó dúró  níwájú àwọn ènìyàn lásán.” Iwe owe 22:29 

Tí o ba ri ẹnití o jafafa ninu ohun ti o ne, o e e e kí irú ènìyàn bẹ jogún ìmọ nínú iẹ tí o  kọ. A kọ e mọ e ní irú ènìyàn náà, ẹnití a ne àpèjúwe rẹ, tí o ne àfihàn àti amọdun jù nínú  ohun ti o kọ. 

 A lè sọ nipa irú ènìyàn bẹ, bí ẹnití o ti la orisirisi idanileko kọjá, kí o tó lé dé ipele ti o ga  nínú iẹ tí o yan laa yo . 

 Yálà nínú èmi tàbí nínú ará, nínú ohun tí a bá fẹ́e, anilati gbà, latí ní ẹkọ rẹ: yọnda ará  rẹ fún idanileko. Awon ọmọ ẹhìn wá ní abé idanileko kí a tó pé wọn ní àpọsítélì.  Iẹ kíkọ gbà òpòlopò igbiyanju atí ifọkansi, lẹhin rẹ o o gbà ọgbọn, ìmọ àti òye láti dì ọgá  nínú àwọn ojúe rẹ. 

e àgbéyẹ̀wò ninu orin, ká akosori nínú ẹsẹ bíbélì leralera; kọ bí a ti ne ikede lati jere  ọkàn, bere fún, kí o sí gbà ìbáwí. Kọ ẹkọ nínú iẹ ìjọ, gbà ẹkọ nínú iẹ igbani niyanju. Tẹle imọran emi mímó, kọ ẹkọ láti ọdọ àwọn ènìyàn Ọlọrun, ao sì sọ ọ di alágbára nípa  ẹkọ. 

ADURA 

Oluwa rán mi lọwọ láti lo àsìkò idanileko àti ikẹkọ mi daradara ni orúkọ Jésù Amin

BIBELI KIKA: Owe 4:1-13 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *