DON’T GIVE UP

 

DON’T GIVE UP

THE SEED 

“Yes, my soul, find rest in God; my hope comes from him. Truly He is my rock and my  salvation; He is my fortress, I shall not be shaken. My salvation and my honour depend  on God; He is my mighty rock, my refuge.” Psalms 62:5-7 (NIVUK).  

Situations and happenings around us sometimes may not be encouraging. There might  not be much news in the media to cheer up one’s soul. It may seem as if ones’ prayers have not  been answered. To some people, they might say there is no point praying again, but wait a  minute, do not lose hope, and do not give in to the stress and pressure of this world that wants  to damage your faith and hope in God.  

Do not give a listening ear to the devil and his co-workers who want you to doubt the  work of hope and grace bought with the blood of Jesus Christ.  

Our hope is not in this world alone, but it also extends till eternity because of the great  works of salvation that were exhibited on the cross of Calvary. 

Nothing in this world is dependable, be it living and non-living. They are subject to  change as many times as possible. However, God is the only sure person that is dependable  and reliable. You can take His words for it and place your hope on Him. 

PRAYERS 

I receive the grace to be steadfast and not give up in life in Jesus name. Amen. BIBLE READINGS: 2 Cor. 4:5-18 

MÁṢE DÁRA RẸ DÚRÓ 

IRÚGBÌN NÁÀ 

“Ọkàn mí iwọ sa dúró jẹ dé Ọlọrun; nitori láti ọdọ rẹ wá ní ìrètí mí. Oun nìkan li apáta mi  àti ìgbàlà mí: òún ní àbò mi: a kì yóò sí mí ni ipò. Nípa Ọlọrun ní ìgbàlà mí, ati ògo mi:  àpáta agbára mi, àbò mi sí mbè nínu Ọlọrun.” (Orin Dáfídì 62:5-7) 

Àwọn ìẹlẹ tí o ne ni àyíká wá nigbamiran lè má dùn mọ wá. Àwọn irohin miran tí o sí  njade láti inú ẹrọ alagbeka lè má mú ayọ bá wá. Tí yíó fi dàbí ẹnipe ádùrá wá kò gbà. Àti lẹ le sọ fún ẹlòmíràn pé o kò nilo lati gbàdúrà mọ, e suru fún ará rẹ, máe sọ ìrètí nu,  má sí e gba irẹwẹsi laaye; tàbí àwọn ìdààmú ọkàn l’otun l’osi, tí o le fẹ bá ìgbàgbọ rẹ jẹ ninu  Olorun. 

e fi etí sí èù àti àwọn alabaiẹpọ rẹ, ti o fẹ kí o e iyemeji ninu ìrètí ati ore-ọfẹ ti a rà  pẹlu ẹjẹ Kristi. Ìrètí wà kò sí nínú ayé nìkan ùgbọ́n o tan titi dé ayérayé, nítorí iẹ nla ìgbàlà tí a  e, e àfihàn rẹ lórí ìgi agbelebu. 

Kò sí ohun tí o wà titi lailai, yálà ohun ti o nmì tàbí tí kò mí, ìyípadà leè dé bá wọn ní ọpọ ìgbà. Olorun nikan ní o dájú, ti a sì leè fokan tan. O lè gbà ọrọ Rẹ, kí o sí gbẹkẹle. ADURA 

Mó gbà ore-ọfẹ lati duro inin, nko sí ní dá àrà mí dúró nínú ayé lórúko Jésù Àmín 

BIBELI KIKA: 2 Cor. 4:5-18 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *