PRICELESS KEYS
THE SEED
“Jesus saith unto him, I am the way, the truth, and the life: no man cometh unto the Father, but by me.” John 14:6
There are three main keys worthy of possession: Way, Truth, and Life.
Everyone is calling on God, but there are ways to do it to get positive feedback. Jesus Christ is that way. Jesus Christ is the truth. Many thinks life is all about the natural life, but Jesus is the life beyond this present world. When God speaks, it becomes the standard at which all things are measured. All men are regarded as dead without Jesus Christ of Nazareth.
The life here refers to eternal life which can only be found in Jesus Christ. This eternal life is the only key to heaven. Furthermore, many people are living in bondage of all kinds under the pretext of religious doctrines because they are ignorant of the truth.
The question is, what is the truth? The truth is the Word of God, John 17:17; the truth is Jesus Christ of Nazareth, John 1:14. Therefore, anyone who wants to be free should know Christ and His word (John 8:32″). What shall it profit a man if he gains the whole world but loses his own soul?
Dearly beloved, choose Jesus now, save yourself from future damnation and you would have these three most priceless keys in life.
PRAYER
Father Lord, give me the grace to know you as the truth and Life, in Jesus name Amen. BIBLE READINGS: John 14:1-6
ÀWỌN KỌKỌRỌ AIDIYELE.
IRÚGBÌN NÁÀ.
“Jésù sí sọ fún ùn pé, Èmi lí ona, ati òtítọ àti iye: kò sí ẹnikẹ́ni tí o le wa sọdọ Bàbá, bikose nípasẹ mi.” Johannu 14:6
Awọn kòkòrò méta tí o yẹ láti ní: Ona, Òtítọ àti Iye. Gbogbo eniyan ni o npe Ọlọrun, sùgbón àwon ọna kàn wà tí a lè fi pé, kí a sì rí èsì idaniloju. Jésù Kristi sí ní ọnà náà. Jésù Kristi ni òtítọ, ọpọ nro pe ayé nikan ní ayé, sugbon Jésù nìkan ni ayé tí o wà lẹhin ayé yí. Nigbati Olorun ba sọrọ yíó dúró bí ọpagun ti a fi nwọn ohun gbogbo. A ka gbogbo eniyan sí òkú, láìsí Jésù Kristi ti Nasareti.
Iye yí ní, a ka sí ìyè àìnípẹkun tí a lè rí nínú Jésù Kristi. Ìyè àìnípẹkun yí ní kòkòrò sí ọrùn. Siwaju síi ọpọ eniyan ni o ngbe ninu orisirisi ìdè labẹ esin igbagbo: nitori won kùnà láti mọ otitọ. Ibere ni pé kíní òtítọ? Otitọ ni ọrọ Olọrun. Johannu orí kẹta din ni ogun ẹsẹ ìkẹta din ni ogun fi yé wa pé Jésù Kristi ti Nasareti ni òtítọ. Nitorina ẹnití o bá ní itusile gbọdọ mọ Kristi àti ọrọ Rẹ (Johannu 8:32) Kíní ere eniyan ti o bá jere gbogbo ayé yí tí o sí sọ èmí rè nù. Àyànfẹ́yan Jésù nisisiyi ki o sí gbà ará rẹ silẹ kúrò nínú ìdájọ tí o mbọ, óò sí ní kòkòrò aidiyele mẹta yí nínú ayé.
ADURA
Oluwa fún mi ni oore-ọfẹ lati mọ otitọ ati ìyè ni oruko Jesu Amin.
BIBELI KIKA: Johannu 14: 1-16