DON’T BE HASTY TO GIVE COMMENTS
THE SEED
“Let your speech be always with grace, seasoned with salt, that ye may know how ye
ought to answer every man.” Colossians 4:6
We are in the era of information freedom and as such there are so many information
mediums available today than ever in the history of life. This development has and is helping a lot of people to advance while it is also destroying a lot of homes and individuals. It is easier now to send information around, but unfortunately much of such information ends up causing more confusion and destruction to people’s lives. As a child of God, you must be disciplined with social media.
Don’t expose yourself or your family carelessly on social media or try to settle a misunderstanding therein. Choose what to view and listen to, don’t make careless comments
on other people’s posts. Abstaining from negativity on social media will help you live a more
peaceful and focused life. Intelligent people spend less time on social media, how much more
the spiritually intelligent. In John chapter 8, some people brought a woman to Jesus with a
secret agenda. Jesus who understood, did not make comments in a hurry. Rather He took his
time to come up with the answer that put them to flight. Don’t be in haste to comment, and if you must, let it be guided by God’s words; apply the wisdom of God in all you do and speak.
PRAYER
Father Lord, let my words be seasoned with salt and grace. Amen.
BIBLE READINGS: John 8:1-10
LORA LATI FÈSÌ, KÍ O MÁ BÀA WONU ÀṢÌṢE.
IRÚGBÌN NÁÀ
“É jẹ kí ọrọ nyìn kí o darapọ̀mọ ore-ọfẹ nigbagbogbo èyítí a fí iyò dun, ki eyin ki o le mọ bi
eyin o tí màá dá olukuluku eniyan lohun ” Kolese 4:6
Àsìkò ti a wa yi jẹ akoko ti’ a faye gba ìkéde iroyin awọn ohun tí o nsele káàkiri. Awọn
ọna ti a sì ngbà ṣe ìkéde yi pọ jù atehinwa. Iru òlàjú yí ti mú ìtẹ̀síwájú bá iṣẹ ọpọ eniyan. O tún jẹ́ òkùnfà ohun tí o ndá ilé ọpọ ẹlòmíràn ru, ti o sí nba ayé wọn jẹ. Lẹhin igbati o rọrun lati fi awọn iroyin wọnyi ranṣẹ kíri, o wà se ni laanu pé àwọn irohin wọnyi máa nyori si rudurudu; ati ibà ayé ènìyàn jẹ. Gẹgẹ bí ọmọ Ọlorun a gbọdọ ko ara ẹni ni ijanu, nípa lílo àwọn èrò a mú ayé dì rọrun.
Lọnà kini, ma gbe ará rẹ tàbí àwọn ẹbí rẹ s’aye lori ẹrọ alagbeka. Lọnà keji nípa lílo àwọn èrò láti parí rukerudo ti o nlọ. Yan ohun tí o tọ latí wo àti láti fèsì.
Pipa ará ẹni mọ kúrò nínú ohun tí o lòdì, lórí ẹrọ yi, yíó mu ọ gbe ìgbé ayé alaafia, atí eyi
ti o ye koro. Awon olóyè eniyan nínú ará máa nlo àsìkò perete lóri ero igbalode yi: melomelo ni ti awọn amòye ninu èmí. Ninu iwe Johannu orí kẹjọ a ri bi awon opo eniyan kán ṣe mú obìrin kàn wà sọdọ Jesu, pẹlu èrò ìkọkọ lati mu Jesu. Èyí jẹ iṣẹ èṣù! Jésù tó mọ èrò ọkàn wọn kò fèsì ní nkankan; dipo eyi o fí ara balẹ láti fún wọn ní èsì tí o tọ tí yíó tu wọn ká. Ma ṣe kánjú lati fèsì, tí o bá sì ṣe pàtàkì láti ṣe bẹẹ, jẹki oyè ọrọ Olọrun tọ ọ. Lo ọgbọn Ọlọrun ninu ohun gbogbo tí o bá nṣe tàbí tí o bá nsọ.
ÁDÙRÁ
Oluwa jeki ọrọ ẹnu mí dàpọ mọ ore-ọfẹ ati iyọ. Amin.
BIBELI KIKA: John 8: 1-10