Utilise What Is Left

                                                   UTILISE WHAT IS LEFT
THE SEED
“…Blind Bartimæus, the son of Timæus, sat by the highway begging. And when he heard
that it was Jesus of Nazareth, he began to cry out..” Mark 10:46-47 KJV
In search of what is lost, you need to draw strength from what is left. Unfortunately,
many focus so much on what is lost so much that they are blinded by the opportunities opened to them to do great things with what they have.
In the above scripture, Bartimaeus, a blind man, pulled strength from what he had by
making use of his voice and legs to seek deliverance from his state of blindness. Also, Naaman a honourable man, great and mighty man of valour, a commander in the army, through whom God gave his nation many victories in war against their enemies, he was a leper. (1King 5:1).
Naaman was physically challenged, but he was mentally sound such that he was the war
strategist of his nation. Naaman had to pay less attention to his challenge (what was lost) but
rather focused on his ambition and determination.
People may point you to your weakness than to your strength; they can also use your
deficiency against you than use your strength for you. It is your responsibility to work on the
areas of your strength and project them in such a way that you are never intimidated by your
weakness. Be productive with what you have. Don’t be stopped by what you lack.
PRAYER
Oh Lord, give me the grace to focus on what I have left in Jesus name. Amen
BIBLE READINGS: Mark 10:46-52

                                         LÓ OHUN TÍ O KU SÍ OWO RẸ

IRÚGBÌN NÁÀ 
“Bartimeu afọju, ọmọ Timeu, joko l’ẹba ọna o nsagbe. Nigbati o gbọ́pé, Jésù tí Nasareti
ní, o bẹrẹ sí ikigbe lohùn rárá, wípé Jésù iwọ ọmọ Dafidi saanu fun mi.” Marku 10:46-47
Ninu wíwá ohun tí o sọnù, o nilo lati wa agbara nínú eleyi tí o kù. O ṣe ni laanu wipe ọpọ
li o nteju mọ ohun ti o ti sọnù; èyí tí o fo wọn lójú, sí àwọn ànfààní ti o sí silẹ fún wọn láti ṣe
takuntakun pẹlu ohùn ti won ní.
Nínú ìwé tí a kà, Bartimeu okunrin afọju, lo ipá rẹ pẹlu ohùn ti o ní; n’ipa lílo ohùn ati ẹsẹ
rẹ, lati wa itusile kúrò nínú ifọju rẹ. Bakanna ni Naamani olórí ogun ọba Siria, eniyan nlá,
alagbara, akọni ọkunrin; nípa ẹnití Ọlọrun fún orilẹ ède rẹ ní ìṣẹgun púpọ lori ogun ọta wọn,
sugbon adẹtẹ ní.
Naamani jẹ ẹnití o ní idojukọ nínú ará ṣùgbón o jẹ olopolo pípé tó bẹẹ tí o fí mọ ọnà àti
jagun ṣẹgun fún orile-ede rẹ. Naamani ko kọbi ara sí idojukọ ti o ní (eyiti o túmọ sí ohun tí o
sọnù). Sugbon dipo rẹ o kọjú mọ ohun tí o jẹ lógún lati ṣe.
Awọn eniyan lè máa tọka rẹ sí ohun ti o ṣe ailagbara lori rẹ, ju ohun tí o lagbara lati ṣe,
wọn sì tún lè lò otitọ rẹ ṣe lodi si ipá rẹ. Ojúṣe rẹ ni lati ṣiṣẹ lórí ipá rẹ lati lo sí ònà ti o tọ. Ti a kò ní fí bu ẹnu àtẹ lu ailagbara rẹ. So eso tí o dara pẹlú ohun tí o ni, máṣe jeki a da ọ l’agara pẹlu ohùn ti o ṣe alaini rẹ.
ADURA
Oluwa fún mi ni ore-ọfẹ lórí ohun tí o sẹku fun mi. Ni orúkọ Jésù Àmín
BIBELI KIKA: Marku 10: 46-52

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *