Your Past Is The Past

THE SEED

“When I was a child, I spoke as a child, understood as a child, and thought as a child: but when I became a man, I put away childish things” 1 Corinthians 13:11

When Apostle Paul said “when I was a child, I talked, thought, and reasoned like a child. Now I am a man, I put all childish ways behind me”, he was describing the forward and upward journey of a Christian. Remember this powerful defender of the Faith was at one time a murderer and persecutor of Christians. But after he met Jesus, he realised he could not do anything to change his past, but he could make the best use of the present for a glorious future. Are you still living in the mistake of your past? Do not allow the misdeed of your past to get in the way of your life. If you remain in your past, you will lose sight of the greatness that God has ahead for you. When you accept Jesus, you become a new being with a new understanding. There’s nothing wrong with learning from your past but it is unprofitable to dwell in the past. If a driver looks through his rear-view mirror more than he looks through his windshield, a crash is inevitable. Think about this.

PRAYER

God, give me the strength to grow from my past into the glorious future You have prepared for me. Amen

BIBLE READINGS: Philippians 3:1-14

OHUN ATIJO NINU AYE RE, OHUN TO TI KOJA NI

IRUGBIN NAA

“Nigba ti mo wa li ewe, emi a maa soro bi ewe, emi a maa moye bi ewe, emi a maa gbero bi ewe: sugbon nigba ti mo di okunrin tan, mo fi iwa ewe sile.” – I Korinti 13:11.

Nigbati Paul Aposteli so wipe “Nigba ti mo wa li ewe, emi a maa soro bi ewe, emi a maa moye bi ewe, emi a maa gbero bi ewe: sugbon nigba ti mo di okunrin tan, mo fi iwa ewe sile”, o nse apejuwe irinke rindo irin ajo onigbagbo. Ranti wipe eniti o n fi gbogbo agbara re pa igbagbo mo yii je apaniyan, eniti maa nse inunibini si awon kristeni nigba kan ri. Sugbon o ba Jesu pade, o si mo wipe ohun ko le se ohunkohun lati yi ise re atijo pada sugbon o seese fun un lati bere sini lo aye re fun ojo ola ti o logo. Nje o si ngbe ninu asise re atijo? Mase je ki asise re atijo ki o dena aye re. Bi o ba duro sinu asise re sibe, o ki yio le ri ipo ogo nla ti Olorun ti pese sile fun o. Logan ti o ba ti gba Jesu, o ti di eda titun pelu oye titun. Ko si ohun ti o buru bi o ba ko eko lati ara asise re atijo sugbon ko dara ki o maa gbe inu re. Bi awako ba nwo awojiji ti n fi ohun to wa leyin han ju bi o ti nwo iwaju lo, o see se ki o ni ijaamu oko. Gba eyi ro.

ADURA

Olorun, fun mi lokun lati dagba kuro ninu igba atijo aye mi sinu ojo ola ti o logo ti o ti pese fun mi. Amin

BIBELI KIKA: Filipi 3:1-14

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *