The Uninterrupted Joy Of God

THE SEED

“When anxiety was great within me, your consolation brought me joy.” Psalms 94:19 NIV

As a child of God, your divine-given joy should not be controlled by physical events of life. We need to keep fit in the Lord by enjoying uninterrupted divine joy. The world is full of
anxiety and evil occurrence, but the source of our joy is in the fact that we belong to God and God is with us in all our challenges to give us a timely solution. It is normal to experience
anxiety because we are human beings, but we must not allow anxiety to penetrate our lives to take away our joy. Our uninterrupted joy is a source of strength that keeps us going come what may. Also, it makes us live a full circle of life. The enemy is aware of this too, and that is why they will do everything in their power to attack the source of our strength to make us
vulnerable to their attacks. As children of God, we must remain in the joy of the Lord and always stay close to the source who is Jesus Christ so that we may live a fulfilling life.

PRAYER

Father in Jesus’ name, let your divine joy continue to be my strength. Amen

BIBLE READINGS: Habakkuk 3:17-19

AYO ỌLỌRUN TI KO NIPEKUN

IRÚGBÌN NÁÀ

“Ninu ọ̀pọlọpọ ibinujẹ mi ninu mi, itunu rẹ li o nmu inu mi dùn.” Orin Dafidi 94:19 BM

Gẹgẹ bíi ọmọ Ọlọrun, awọn ìrírí ayé ko gbọdọ jẹ alakoso ayo wa. A ni lati duro ninu Oluwa ki a le ma gbádùn ayọ atokewa. Ayé yìí kún fún àníyàn ati iṣẹlẹ búburú, sugbon orisun ayọ wa ni o wà nínú pe awa jẹ ti Ọlọrun, Ọlọrun sì wà pẹlu wa ninu gbogbo idojukọ wa, láti fún wa ni ojútùú lakoko rẹ̀. Ko ṣe àjòjì lati ni ìrírí àníyàn nitoripe a je eniyan, sugbon a ko gbọdọ jẹki àníyàn kí o gba ayé wa tobē, tí yíò mú ayọ wa kuro. Ayọ àìnípẹkun wa jẹ orísun okun fún wa láti má mú wa tẹsiwaju bi o tile wù kí o ri. Bakanna o nmu wa gbe igbe ayé kikún. Awon ọ̀tá ẹ̀mi wa mọ eyi pẹlu. Nitorina ni won ma n ṣe ohun gbogbo ninu àgbàrá won lati dojukọ orisun okun wa, ki won le ṣe ìpalára fún wa. Gege bíi ọmọ Ọlọrun, a gbọdọ wà nínú ayo Oluwa ki a sì dúró pẹlú orísun wa, eniti n ṣe Jesu Kristi, ki a le gbe ìgbé ayé imuṣe.

ÁDÙRÁ

Baba, ni oruko Jesu, jékí ayọ rẹ lati òrun wa mā ṣe agbára mi.

BIBELI KIKA: Habakkuk 3:17-19

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *