Are You Walking With God Like Them?

THE SEED

“The name of the man was Nabal and the name of his wife Abigail. And she was a woman of good understanding and beautiful appearance, but the man was harsh and evil in his
doings. He was of the house of Caleb.”1 Samuel 25:3 NKJV

It’s not uncommon to see the descendants of people that serve God being indifferent to God. Such is the case of Nabal the husband of Abigail. He was a descendant of Caleb, one of the spies that were sent to spy on the promised land and one of the two that came back with a good report. He believed in God and worked to support Moses the man of God. Nabal is the total opposite of Caleb in all things. His way of life was the carnal and selfish one, but because of Caleb’s walk with God, Nabal enjoyed the generational blessing that God pronounced upon Caleb and his generation. As Christians, are we faithful in serving God like our forefathers did or we are clouded by the blessings that we enjoy from their services to think that we know God?
We need to know and be sure of our position with God to avoid the judgment of God that says “I know ye not, you workers of iniquity.”

PRAYER

God, please enable me to serve you wholeheartedly more than anyone that existed in my family. Amen
BIBLE READINGS: 1 Samuel 25:1-11

 NJẸ O NBA ỌLỌRUN RIN BĪ TIWON?

IRÚGBÌN NÁÀ

“Orukọ ọkunrin na si njẹ Nabali, orukọ aya rẹ̀si njẹ Abigaili; on si jẹ oloye obinrin, ati arẹwa enia; ṣugbọn onroro ati oniwa buburu ni ọkunrin; ẹni idile Kalebu li on si ṣe.” 1 Samueli 25:3 BM

Kī ṣe àjòjì lati ri iran awọn eniyan ti won ti sìn Ọlọrun, ti ko rin dede níwájú Ọlọrun. Iru eniyan báyìí ni Nabali, ọkọ Abigaili jẹ. Nabali jẹ iran Kalebu, ọkan ninu awọn àmì ti won ran lọ
silẹ ìlérí. O sì jẹ ọkan nínú àwọn meji ti o mu ìròyìn didara pada wa. Kalebu gba Ọlọrun gbọ, o sì ṣiṣe pẹlu Mose eniyan Olorun. Sugbon, igbe ayé Nabali je idakeji tirẹ ninu ohungbogbo. O gbe ìgbé ayé ara ati ìmọ-tara-eni-nikan. Sugbon, nitori irin dédé ti Kalebu rin níwájú Ọlọrun, Nabali j’ola awọn ìbùkún iran deran ti Olorun fifún ìràn Kalebu. Bíi Kristẹni, nje awa jẹ olotitọ ninu ìsìn Ọlọrun bí àwọn aṣáájú wa ti ṣe? Tabi, awọn ìbùkún tí a ri gba nipasẹ iṣẹ ìsìn wọn sì Ọlọrun njẹ ki a ro wipe a mọ Ọlọrun? A gbọdọ mọ dájúdájú ipo ti a wa pẹlu Ọlọrun ki a ma bā jẹ alabapin ninu ìdájọ Ọlọrun ti o sọ pe “Emi ko mọ ọ ri, iwo oníṣe ẹṣẹ!”

ÁDÙRÁ

Oluwa, é jọwọ, ẹ́ranmilọwọ lati sìn yin tọkàntọkàn ju ẹnikẹni nínú iran mi lọ. Amin.

BIBELI KIKA: 1 Samuel 25:1-11

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *