THE SEED
“Be still before the Lord and wait patiently for him; ….” Psalms 37:7aNIV
King David, a man of great and diverse experience, says in Psalm 37 above that we have to be still before God and wait patiently to attain a victorious end. He walked with God all the
days of his life in patience, and we can’t take light his words of experience. He exhibited great patience in waiting for God to make things happen in his life in God’s time. He was anointed a King over Israel to take over the throne from King Saul, but he patiently waited years for God’s appropriate time. David was a famous and great warrior and loved by people, but he didn’t allow himself to get carried away with this but continued to wait patiently on God. When king Saul sorted to kill him, instead of using his influence to overthrow him, he preferred to become a fugitive in the wilderness and neighbouring countries, waiting on God for victory, and not allow the heat of the moment to deprive him of God’s given victory through impatience.
Brethren, we need to walk with God in enduring patience to attain God’s given victory
over our situations.
PRAYER
Lord, I ask for the patient to walk with You to be able to wait to receive Your given victory over my challenges in Jesus’ name. Amen
BIBLE READINGS: Psalm 37:1-11
SÙÚRÙ TI O MU ÌṢẸGUN WA
IRÚGBÌN NÁÀ
“Iwọ simi ninu Oluwa, ki o si fi sũru duro dè e…” Orin Dafidi 37:7A BM
Oba Dafidi, eni tí o ni oniruuru iriri sọ ninu iwe Orin Dafidi 37, ti o wà lókè yìí wipe, a ni lati duro níwájú Ọlọrun ki a sì wá ni sùúrù kí a lè ni opin ti o dara. Oba Dafidi jẹ ẹnití o ba Ọlọrun rin ni gbogbo ọjọ ayé rẹ ninu sùúrù, nitorina, a ko lē ko ọrọ ẹrí rẹ danu. O fi sùúrù nla hàn wa nipa diduro de Ọlọrun lati ṣe ohun gbogbo ni akoko Ọlọrun ninu ayé rẹ. A fi àmì òróró yan-an gẹgẹ bíi ọba lori Israẹli lati gba itẹ kuro lọwọ ọba Saulu, sugbon o duro de Ọlọrun fún ọpọlọpọ ọdun. Dafidi je gbajumọ ati jagunjagun nla ti awon eniyan fẹràn, sugbon ko jẹko awọn ohun wọnyi di oun lọwọ, sibẹsibẹ o duro dè Oluwa ninu sùúrù. Nigbati ọba Saulu nwaa lati pa, kàkà kí o lo anfani ti o ni yìí láti gba ìjọba lọwọ rẹ, o ṣetan lati di enití n sa kiri ninu aginjù ati awọn orilẹ-ede miran lati duro dè Ọlọrun fún ìṣẹgun, ju ki o gba idojukọ rẹ l’áyè lati mu kí o sọ ìṣẹgun Ọlọrun nu. Ara, a nilo lati mā ba Olorun rin ninu sùúrù, ki a le gba ìṣẹgun lórí gbogbo idojukọ won.
ÁDÙRÁ
Oluwa, mo bèrè fún sùúrù lati ba ọ rin ki n le duro lati gba ìṣẹgun lati ọdọ rẹ lori gbogbo idojukọ mi, lórúko Jesu. Amin.
BIBELI KIKA: Orin Dafidi 37:1-11