THE SEED
“Let no man despise thy youth; but be thou an example of the believers.” 1 Timothy 4:12
In the world today, people no longer want to hear only the words we proclaim. Rather they want to see how we relate with people around us. Nobody wants to do what you say, but what you do. Jesus became our perfect example when He came to the world as a man. He went about doing good, seeking those who were lost and helping the helpless. How are you going about your Christian journey? Do you say one thing and do another? Do you preach to others what you know you can’t do? I have seen a lot of people who said they can’t follow certain people to church because of their characters. Dear reader of this devotional, are you a worthy example of a believer that Christ can be proud of? Can people say of a truth that you are a man or woman of your words? God said of Abraham “for I know him that he will command his children and his household after him and they shall keep the way of the Lord to do justice and judgement that the Lord may bring upon Abraham that which I had spoken of him” Genesis 18:19. Beloved, to be a true epistle of Christ, you must demonstrate Christ’s unfeigned and unconditional love for others. You must forgive others as Christ forgave you. You must also be willing to bear the burden of others at all times. In other words, people must see Jesus in you.
PRAYER
Father Lord give me the grace to be a life-changing and impactful epistle that all will read and follow Christ in Jesus name. Amen
BIBLE READINGS: 1 Timothy 4:1-16; Matthew 5:13-16
JE IWE TI ARAYE N KA
IRUGBIN NAA
“Mase je ki enikeni ki o gan igba ewe re, sugbon ki iwo ki o je apere fun awon ti o gbagbo, ninu oro, ninu iwa hihu, ninu ife, ninu emi, ninu igbagbo, ninu iwa mimo.” I Timoteu 4:12
Ninu aye loni, awon eniyan ko fe lati maa gbo oro enu wa nikan, sugbon won fe lati ri bi iwa wa se ri si awon ti o sunmo wa. Ko si eni ti o fe lati se ohun ti a n wi, sugbon eyi ti a nse. Jesu je apere pipe fun wa nigba ti o wa saye ni aworan eniyan. O n se rere kaa kiri. O n wa awon agutan ti o sonu, o si ran awon alaini lowo. Bawo ni iwo se n rin irin ajo igbagbo tire? Nje iwo a maa so ohun kan ki o si maa se ohun miran? Nje iwo nwaasu ohun ti o mo wipe o ko le se? Mo ti ri opo eniyan ti nwon wipe won kole tele awon kan lo si ile ijosin won nitori iwa won. Iwo olufe ti o nka iwe yii, iwo na je apeere rere ti Kristi le fi yangan bi? Nje awon eniyan le so ni otito ati ododo wipe iwo je okunrin tabi obinrin ti n se ohun ti o wi bi? Olorun wi niti Abrahamu pe “nitoriti mo mo o pe, on o fi ase fun awon omo re ati fun awon ara ile re lehin re ki nwon ki o maa pa ona Oluwa mo lati se ododo ati idajo, ki Oluwa ki o le mu ohun ti o ti so fun Abrahamu wa fun u” Genesisi 18:19. Olufe, lati je iwe ti aye nka, to si n fi Jesu han, o gbodo fi ife aisetan,ti Olorun han fun awon eniyan, o gbodo dariji gege bi Kristi ti dariji o. o si gbodo setan lati ran awon eniyan lowo pelu isoro won ni igba gbogbo. Eyi ti o tunmo si wipe, a gbodo ri Jesu ninu aye re.
ADURA
Baba Oluwa, fun mi ni ooreofe, ti n o fi je iwe ti n yi aye eni pada, ti awon eniyan yio ka, ti won yio si tele Kristi, ni Oruko Jesu, Amin.
BIBELI KIKA: 1 Timotiu 4:1-16; Matteu 5:13-16