Know And Be Conscious Of Your Purpose

THE SEED
“Jesus saith unto them, my meat is to do the will of Him that sent me, and to finish His work.” John: 4:34.

Genesis 6:2 says, “that the sons of God saw the daughters of men that they were beautiful and they took wives for themselves of all whom they chose.” This shows us the failure of some ordained people called to fulfil a divine purpose on earth, who failed because they were cornered by the spirit of lust. Samson was a good example. His attention was diverted by lust such that he lost his purpose on earth. Revelation 4:11 reveals that God created us for His pleasure to do His will. We must never allow the cares of this world or lust in the world to divert us from living a life for which God created us. Christ in today's text is absolute and definite about His origin and purpose on earth. Like Christ we must be conscious of our identity, origin and mission. We must live with the consciousness of why we are sent into this world, the purpose for which we are sent and by who. Such consciousness will help us work in the reality of our purpose on earth. It is not enough to know our divine purpose on earth, we must strive to fulfil it even as Christ did. We must go about the purpose and knowing that even as God has sent you the devil as well has sent his agents to distract you. This is why you must partner with the Holy Spirit who releases the grace you need to do the will of God on earth and to finish it.

PRAYER
Oh Lord let me live according to Your purpose on earth.
BIBLE READINGS: Genesis 6:1-6; Ephesians 2:1-10

MO, KI O SI SE AKIYESI IDI IWASAYE RE

IRUGBIN NAA
“Jesu wi fun won pe, onje mi ni lati se ife eniti o ran mi, ati lat pari ise re.” Johannu: 4:34

Genesisi 6:2 so wipe “Ni awon omo Olorun ri awon omobinrin eniyan pe, nwon lewa, nwon fe aya fun ara won ninu gbogbo awon ti won yan”. Eyi fi ijakule die ninu awon ti a yan lati wa se ise pataki kan tabi ekeji laye sugbon ti won kuna nitori ifekufe aye han. Samsoni je apeere pataki, ifekufe ara ni o gba okan re to bee ti o fi kuna lori ise ti a ran wa se laye. Ifihan 4:11 fihan wipe Olorun da wa nitori ife inu re ki a le se ife re. A ko gbodo je ki aniyan aye tabi ifekufe re ki o mu wa ya kuro ninu gbigbe igbe aye ti Olorun tori re da wa. Ninu ese Bibeli ti a ka ni ibere eko yii, a ri pe Kristi ni idaniloju nipa ibi ti o ti wa ati idi iwasaye re.
Gege bi ti Kristi, a gbodo kiyesi idanimo wa, orisun ati ise ti a ran wa. Ki a gbe igbe aye wa ni ikiyesara, nipa idi iwasaye wa ati eni ti o ran wa. Iru ikiyesara yii, yio ran wa lowo lati le se aseyori ise ti a ran wa saye lati se. ki ise fun wa lati mo idi iwasaye wa nikan sugbon ki a tiraka lati muuse gege bi Kristi ti muu se. A gbodo gbiyanju lati se ohun ti a ran wa ki a si mo wipe gege bi Olorun ti ran wa, bee gege ni esu ran awon iranse re lati mu wa kuna. Idi niyi ti a fi gbodo ni Emi Mimo eniti n fun ni looreofe ti a nilo lati se ife Olorun laye ki a si yori re daradara.

ADURA
Oluwa, je ki n gbe igbe aye mi ni ibamu pelu ife re laye. Amin
BIBELI KIKA: Genesisi 6:1-6; Efesu 2:1-10

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *