THE SEED
“The Spirit of the Lord is upon me, because he hath anointed me to preach the gospel to the poor; he hath sent me to heal the broken-hearted, to preach deliverance to the captives, and
recovering of sight to the blind, to set at liberty them that are bruised,” Luke 4:18
Jesus came here on earth as the anointed One that came to set the captives free from every lie of satan who is the enemy of the children of God. These captives which are to be set
free are prisoners of the devil/satan. They are in satan’s labour camp, being forced, as slaves to do his bidding. They are in chains of bondage, and there is nothing they can do about it. God’s anointing was on Jesus and the anointing was so strong, that Jesus the anointed one went about healing all those who were oppressed by the devil, and everywhere He went, the captives were set free from every form of illnesses or diseases. Dearly beloved, the anointing on Jesus caused Him to do only good to everyone that He met. And because of His love for us who chose Him as our Lord and Saviour, we can be healed from every kind of illnesses and sorrow. Jesus came to set the captive free and heal the broken hearted.
PRAYER
O Lord let your anointing set me free in Jesus name Amen
BIBLE READINGS: Isaiah 61
TITU AWỌN ONDÈ SILẸ
IRÚGBÌN NÁÀ
“Ẹ̀mí Oluwa Jèhófà mbè ní ará mí, nitoriti o fi àmì òróró yàn mí láti wàásù ìhìnrere fún àwọn òtòṣì; o tí rán mí wá láti ṣe ìwòsàn àwọn ọkàn onirobinujẹ, lati wàásù idasilẹ fún àwọn igbekun,
itunriran fún àwọn afọju, ati lati jọwọ awọn ti a pá lára lọwọ.” Luku 4:18.
Jesu wá sí ayé gẹgẹ bi ẹni tí a fi àmì oróro yàn lati tu awọn ondè silẹ, kúrò lọwọ eke satani ẹni tí o jẹ ọtá awọn ọmọ Ọlọrun. Awọn ondè wọnyi jẹ awọn ti a tu silẹ kúrò lọwọ ẹwọn
satani. Wọn jẹ awọn ti o wà ní ikawọ àwọn akoniṣiṣẹ ni ibudo satani, ti a mu ni ipá lati ṣe ìfẹ satani. Wọ́ n wà nínú ṣẹkẹṣẹkẹ igbekun, kò sì sì ohùn tí wọ́ n lè ṣe sí. Ifi ami ororo yàn Ọlọrun wà lára Jesu, ifi ami ororo yàn yi sí ní agbára; tó bẹ́ẹ̀ tí Jésù nfí ami òróró yàn yi, nlọ kiri lati ṣe dídá ara fún àwọn tó wà ní abẹ́ igbekun satani. Ìbí gbogbo ti o bá sì nlọ ní àwọn tí o wà nínú igbekun yí, ngba itusilẹ kúrò nínú àìsàn tabi àrùn. Ẹyin ayanfẹ, ifami ororo yàn Jesu ní o mu kí O máa nṣe rere fún ènìyàn gbogbo ti o bá ṣe alabapade Rẹ. Nitori ifẹ Ọlọrun sí wá, ẹnití o yan Jésù ní Olúwa àti Olùgbàlà wa, ki o lè mú wa larada kúrò nínú oniruru àìsàn àti ipọnju. Jesu wá láti dá àwọn tí o wà nínú igbekun silẹ ati lati tu awọn òtòṣì silẹ
ADURA
Oluwa jẹ ki ifami ororo Rẹ yàn tu mí sílẹ̀. Àmín.
BIBELI KIKA: Isaiah 61