All Things Work Together For Good

THE SEED
“Yet in all these things we are more than conquerors through Him who loved us.” Romans 8:37

Paul guaranteed the Romans that “… we realize that everything works together for good to the people who love God… ” (Romans 8:28). Indeed, even as he wrote those words, Paul
figured out the tensions and torments of this life. He had been whipped, beaten, stoned, wrecked, hungry, stripped, and cold – for the purpose of the Gospel (2 Corinthians 11:23-28). He
was not recommending that those things are good. He was proclaiming that when we look at troubles of life from angle of God’s goodness, it shapes and forms us. We consider battles to be
a season to acquire strength. Unshakable certainty gives our spirits an assurance that God is on His throne, and everything will turn out great. We make the determination to rejoice in the day that God has made, to be glad right now (Psalm 118:24). We are living in an unpredictable world. There are steady disturbances to our “normal life” including sickness, relationship issue, and monetary difficulty. Nonetheless, we have a God who is more prominent than these things and the distractions they cause. Indeed, even in circumstances that satan plans for evil, God will reclaim them to achieve His great purposes. He has caused us to be more than conquerors!

PRAYER
Father Lord, in the freedom I have in you and the hope of eternal life, let everything work together for good in the life of my family and I. Amen!

BIBLE READINGS: 2 Corinthians 11:16-33
OHUN GBOGBO ṢIṢẸ PỌ FÚN RERE
IRÚGBÌN NÁÀ
“Ṣùgbọ́ n ninu gbogbo nkan wọnyi àwa jù àṣẹgun lọ nipa ẹ̀niti o fẹ wá” Romu 8:37

Paulu aposteli fi dá àwọn ará Róòmù lójú pé ” A fìdí rẹ múlẹ pe ohun gbogbo ṣiṣe pọ fún réré nipa ẹ́niti o fẹ Oluwa.” (Romu 8:37) Nitotọ bí o tí ṣe kọ àwọn ọrọ wọnyi, Paulu ṣe àpèjúwe
aibalẹ ọkan ati idaloro ninu ayé yìí. A náa l’ẹgba, à lùu, a sọ ọ lokuta, ìjàmbá ọkọ ojú omi, ebi, ìtùni sí ìhoho ati otutu nitori ìhìnrere. (2Korinti 11:23-28) Ko sọ nípa pé àwọn nkan wọnyi dára, o nfi ye wa pe nigbati a bá nwo awọn wahala ti o wà nínú ayé áti iré tí o ti ọdọ Ọlọrun wá, eyi n mọ́ wá, o sì tún ngbe wá ro. A nwo ogun bíi àsìkò ti a ngba agbara. Ìdánilójú ti kò ní ami-wo; nfún ọkàn wá ní imulọ- kanle pe Ọlọrun wá lórí ìtẹ, ohungbogbo yíó jasi daradara. A ní ipinu lati máà yọ nínú ọjọ tí Olúwa dá, láti yọ ni lọ ọ lọ yí. (Psalmu 118:24) . A ngbe
ninu ayé tí a kò lè sọ nípa ọjọ iwájú rẹ. Àwọn ohun idiwọ kàn duro lodi sí ìgbé ayé wá, awọn nkan bí àìsàn, ọrọ lóri Iba kẹgbẹ pọ, àti wàhálà nipa owó ninà. Sibẹsibẹ, a ni Ọlọrun ti o pọju awọn ohun wọnyi lọ àti gbogbo aí balẹ ọkan ti wọn nfa. Ninu gbogbo idamu ti satani nla kalẹ fún ìbí, Ọlọ́run yíó ló wọn fún aṣeyọri tí o ga. O tí mú wá jẹ ẹ́ni ti o jù àṣẹgun lọ.

ADURA
Bàbá wa nípa ominira ti mo ni ninu Rẹ, àti ìrètí ayérayé, jẹ kí ohun gbogbo ṣiṣe pọ fún réré ninu ayé èmi àti àwọn ẹbí mi Àmìn.

BIBELI KIKA: 2 Korinti 11:16-33

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *