Trials And Tribulations

THE SEED
“Many are the afflictions of the righteous; but the Lord delivereth him out of them all.” Psalm 34:19[KJV]

Tribulations and trials are tests men encounter that proves their stance with God Almighty. It never last because it is not forever, for His words to us that says “there hath no temptation taken you but such as is common to man: but God is faithful, who will not suffer you to be tempted above that ye are able; but will with the temptation also make a way of escape, that ye may be able to bear it” [1st Corinthians 10:13KJV]. We serve a living God that is reliable and dependable, He is always ready to fight and conquer all battles for us. He is a Mighty man in battle, so whenever we go through challenges we have to trust him wholeheartedly, do not weaver or run helter skelter but rely on Him solely, always be like a wise man that built his house on the rock and when the storm comes however wild, the house stands firm but on the other hand a foolish man who did not make God his solid rock is likened to a man that built his house on the sand and when the wind blows the house fell and it was indeed a great fall. Remember Abraham and Sarah that seek for the fruit of the womb at old age did not die childless, Obededom did not likewise die a poor man, also the man at side of Bethsaida river for 38 years did not die of the illness, The Lord made them whole, do not lose hope today, you are the next to TESTIFY HALLELUYAH!!!

PRAYER
Lord, help us to always be strong in our faith to rely, wait patiently and to believe in you that you can do all things for us during our challenges in Jesus Name. Amen

BIBLE READINGS: John 16:16-33

WAHALA ATI ISORO
IRUGBIN NAA
“Opolopo ni iponju olododo, sugbon Oluwa gba a ninu won gbogbo.” Psalm 34: 19

Wahala ati isoro je awon idanwo ti eniyan a maa koju ki o le mo iduro re pelu Olorun. Eyi kii pe lo titi nitori kii se titi aye. Nitori oro Re si wa ni wipe “ko si idanwo kan ti o tii ba nyin, bikose iru eyiti o mo niwon fun enia, sugbon olododo ni Olorun, eniti ki yio je ki a dan yin wo ju bi eyin ti le gba, sugbon ti yio si se ona atiyo pelu ninu idanwo naa, ki eyin ki o ba le gba a. I Korinti 10:13. Olorun alaaye, eniti o see gbarale, ti o see gbokanle ni a n sin. O setan lati jagun ki o si segun fun wa nigba gbogbo. Alagbara ni ogun ni, nitori naa, nigba kigba ti a ba n la idojuko koja, a gbodo gbeke wa le tokantokan, mase se iyemeji tabi sa soke sodo sugbon gbe gbogbo okan re le, maa se bi ologbon ti o ko ile re sori apata, nigba ti iji lile si de, ile naa duro sugbon ni idakeji, eni ti ko fi Olorun se apata re ni a fi we asiwere ti o ko ile re sori iyanrin, nigba ti iji si de, ile naa si wo, wiwo re si po. E ranti Abrahamu ati Sarah ti won woju Olorun fun omo ni ojo ogbo won, won ko si ku li ailomo. Obediedomu ko ku si ipo osi, bee gege ni okunrin ni, leti odo Bethsaida fun odun mejidinlogoji ko ku
sinu aisan, Oluwa mu won larada. Mase so ireti nu loni, iwo ni eri kan. Halleluyah.

ADURA
Oluwa, ran wa lowo ki a le ni igbagbo lati simi le o, lati fi suuru duro de ati lati gbagbo ninu Re wipe O le se ohun gbogbo fun wa ninu awon idojuko wa ni oruko Jesu. Amin

BIBELI KIKA: Johannu 16:16-33

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *