The Covenant Prayer

THE SEED
“Now therefore, if ye will obey my voice indeed, and keep my covenant, then ye shall be a peculiar treasure unto me above all people: for all the earth is mine” Exodus 19:5

Prayer is aligning ourselves with the purposes of God. A covenant with God takes us further into our goal of Christ-likeness. When we make this commitment to consistently communicate with the Father above in prayer, you will begin to see the power of God’s grace actively at work in our lives and in the lives of those around us. A covenant is a sacred agreement between God and His children. God sets specific conditions, and He promises to bless us as we obey these conditions. Making and keeping covenants qualifies us to receive the blessings God has promised. When we choose not to keep covenants, we cannot receive the blessings. Dearly beloved, through this awesome power of covenant prayer, God creates within us a life that He can use extraordinarily in the process of divine redemption. It’s time for us to make this covenant with God as we mature from being simply believers in prayer to becoming a living sacrifice full of the power of covenant prayer.

PRAYER
Father Lord your covenant will forever remain sure in my life in Jesus name Amen

BIBLE READINGS: Exodus 19: 1-25

MAJẸMU ÁDÙRÁ
IRÚGBÌN NÁÀ
“Njẹ nisisiyi, bí ẹyin ba fẹ gba ohùn mi gbọ́ nitotọ, tí ẹ o sí pá Majẹmu mí mọ, nigbana li ẹyin o jẹ ìṣura fún mi jù gbogbo eniyan lọ: nitori gbogbo ayé ní tí èmí.” Eksodu 19: 5

Adura jẹ siso wá pọ pẹlú ìlànà Ọlọrun. Majẹmu pẹlu Ọlọrun mú wa lọ jina sínú ìwà bí Kristi. Nigbati a ba mu ìpinu lati máa bá Bàbá wá oke sọrọ nigba gbogbo; iwọ yíó bẹrẹ sí ní rí agbara ore-ọfẹ Ọlọrun lójú kóró ju nínú ayé wá àti nínú ayé awọn ti o yi wà ká. Majẹmu jẹ adehun ikọkọ laarin Ọlọrun ati awọn ọmọ Rẹ. Ọlọrun ní àwọn alakalẹ pàtó, O sì ṣe ileri lati bukun wá bí a tí nṣe ìgbọràn sí àwọn alakalẹ wọnyi. Ṣíṣe àti pipa Majẹmu mọ, ká wá yẹ láti gba ìbùkún, tí Ọlọrun ṣe ileri fún wa. Tí a bá yan lati má pá Majẹmu mọ́ , a kò lè rí ìbùkún gbà. Olufẹ ọ̀ wọ́ n nípa agbára Majẹmu ádùrá Ọlọrun dá ìwà láàyè sínú wa, ti O le lo fún agbayanu iṣẹ ìràpadà. Àsìkò tí to fún wa láti ní Majẹmu pẹlu Ọlọrun, bi a ti ndagba kúrò nínú jíjẹ onigbagbọ ninu adura; ki a sí jíjẹ ẹbọ ààyè kíkún tí o ní agbára Majẹmu ádùrá.

ADURA
Oluwa jẹ ki Majẹmu Rẹ duro titi Lai nínú ayé mi. Amin.

BIBELI KIKA: Eksodu 19: 1-25

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *