God’s Grace

THE SEED
“Grace and peace be multiplied unto you through the knowledge of God, and of Jesus our Lord,” 2 Peter 1:2

Grace is an exceptional ability to achieve what human ability can’t accomplish. Whatever is your trial, there is enough grace to beat it. Assuming you are going through a difficult time, recall that the grace which you have gotten through Jesus Christ is enough to conquer it. Commonly we think it is faith we want, when in reality it is a greater understanding of
grace. The more the knowledge of what Christ has done, the more we gain God’s love toward us. Living in this total love relationship with God implies we are dependent on God’s grace
and completely surrendered to the power of the Holy Spirit to guide us, strengthen us, safeguard us, and put on us the fear and the will of God.

PRAYER

God grant me the grace to be expose more to your knowledge and overcome trials of life in Jesus name

BIBLE READINGS: Hebrew 4

OORE-OFE OLORUN

IRUGBIN NAA

“Ki oore ofe ati alaafia kio maa bisi fun yin ninu imo Olorun ati ti jesu Oluwa wa.” 2 Peter 1:2

Oore ofe ni agbara lati se oun ti agbara eniyan o le se. ounkoun tio ba je idanwo re, oore ofe wa lati bori re. ni igba ti o ba nla akoko isoro koja, lo oore ofe ti o ti ri gba nipase Jesu lati bori re. Opo igba a ma nlero wipe igbagbo la nilo, sugbon ti oje wipe oye oore ofe ni a nilo. Bi imo wa ba se npo si nipa oun ti Kristi ti se, bee noni ife re yio maa po si fun wa.
Gbigbe ninu ibasepo ife pelu Olorun tumo si wipe a gbe ara le oore ofe Olorun a si jowo ara wa patapata fun agbara Emimimo lati dari wa, lati ro wa ni agbara, lati daabo bo wa ati lati fi wa sinu iberu ati ife Olorun

ADURA

Olorun fun mi ni oore ofe lati ni imo nipa re si ki nsi bori idanwo aye ni oruko Jesu. Amin.

BIBELI KIKA: Heberu 4

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *