Never Underestimate The Power Of God In You

THE SEED
“There hath no temptation taken you but such as is common to man: but God is faithful who will not suffer you to be tempted above that ye are able.” 1 Cor 10:13

Many times, we often underestimate the power that God has deposited in us. When I read the above passage in the book of Numbers chapter 11, I was astonished that out of one man, came out anointing for seventy people and yet MOSES thought he was incapable of leading the people and called that God should even kill him. Also, it is not that all the anointing is finished. Only God knows how many would still be able to take out of the anointing loaded in MOSES alone. Apparently, many of us, our lack of faith in God is because we don’t know the God we serve and the amount of anointing God has deposited in us and often we think we are empty and not up to the task. You can’t imagine the legions of angels deployed to you alone for you to have peace and comfort. You can’t imagine the kind of wisdom God has deposited in you but you are the one also limiting the hand of God in your life. If only we can brace up ourselves, for with God all things are possible (Matt 19:26) Quit underestimating the power of God that has been deposited in you. We don’t fully know the power and glory that God has deposited in us, but we live in fear most of the time. Ps. 53:5

PRAYER
Oh Lord, open my eyes to know my worth in you by Christ Jesus.
BIBLE READINGS: Numbers 11: 10 – 17

MAṢE KẸGAN AGBARA ỌLỌRUN TI O WÀ NÍNÚ RẸ

IRÚGBÌN NÁÀ
“Ko sí idanwo kàn tí o tí bá yín, bikòṣe irú eyiti o mọ níwọ̀ n fún ènìyàn: ṣùgbọ́ n olododo li Ọlọrun, ẹnití kí yíó jẹ kí a dan yín wò jù bí ẹyìn tí le gbà: ṣùgbón tí yíò sì ṣe ọnà àtiyọ pẹlu ninu idanwo naa, ki ẹyìn kí o bá lè gbà a.” 1 Kọrinti 10:23

Ni ọpọ igba ní a máa nkẹgàn agbara Ọlọrun tí a fí sínú wa. Nigbati mo ká nípa ẹkọ tí a kọ akọle ninu iwe Numeri orí ikọkanla; ẹnu yà mí pé lára ẹyọ ọkunrin kan ní a tí rí, ifororo yan fún aadọrin eniyan; sibẹ Mósè ro pe oun kò kún ojú òṣùwọ̀ n láti darí àwọn ènìyàn, o sì kepè Olorun kí a mú òun kúrò. Bẹ gẹgẹ kìí ṣe pé àmì ifòróró yan náà tí tán. Ọlọrun nìkan ní O mọ iye ẹnití yíó gbà lára ifòróró yan tí o wà lára Mósè nikan. O han pé, ọpọ wá tí kò ní ìgbàgbọ nínú
Ọlọrun, túmọ sí láti pé a kò mọ̀ Ọlọrun ti a nsìn; àti bí ifòróró yan Ọlọrun ṣe pọ tó ninu wa. Ọpọ ìgbà ní a sì máa nrò pé a wà lofo tí a kò sí kún ojuwọn láti sìn Ọlọrun. O kò lè forí ṣírò ọ̀ kẹ́ àìmọye awọn angẹli ti a yan ti ọ nikan, kí o bá lè ní àlàáfíà àti ìtùnú. O Ko lè mọ irú ọgbọn Ọlọrun ti a fí sí ọ ninu, ṣùgbón o dín ọwọ Ọlọrun kù ninu ayé rẹ. Tí a bá lè jí gírí, torípé pẹlu Ọlọrun ohun gbogbo ní ṣíṣe (Matiu 19:26). Kúrò nínú ka din agbara Ọlọrun kù tí o ti fí sí ninu ará rẹ. A ko mọ ẹkun rẹrẹ ohun ti Ọlọrun fí sínú ayé wa, ṣùgbọ́ n a ngbe ninu ìbẹrù ní ọpọ ìgbà Psalmu 53:5.

ÁDÙRÁ
Oluwa ṣi mi ni oju, láti mọ bí mó ṣe to ninu Jesu Kristi.
BIBELI KIKA: Numeri 11:10-17

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *