The People Is One

THE SEED
“For as the lightning cometh out of the east; and shinneth even unto the west; so shall also the coming of the son of man be.” Mathew 24:27

God said in Gen. 11:6 that the people of the world was one and of one language, and this they begin to do: and now nothing will be restrained from them, which they have imagined to do. The entire passage was a peep into the end time of the world. And God said, there would be nothing that they will be restrained from them to achieve if left alone. Gradually, the world is growing to being one again, of one language again, by way of internet and technology, artificial
intelligence is being taught in junior schools, for uniformity of knowledge, we now have a global village, what happens in one end of the earth is known the same minute at the other end, e.g music, politics, fashion and every sphere of life. Man is seeking means of escaping death as laid down by God, that the world is a like a market place and all must return to the maker to render account. In the same passage, God had to come down to confuse their language, before they
went far. In the same vein, as the world moving gradually into oneness again, and seeking all manner of knowledge to contradict the will and plans of God, our Lord Jesus will appear in the sky, however, this time not to confuse the language, but to give judgement. Rev.22:12. This is one of end time signs, telling us that the coming of Christ is at hand, so, we should be prepared.

PRAYER
Oh Lord, when you come and collect your people, let me not be found wanting, in Jesus name.
BIBLE READINGS: Genesis 11:1-9

AWỌN ENIYAN JẸ ỌKAN

IRÚGBÌN NÁÀ
“Nitori gẹgẹ bí manamana tí ikọ láti ìlà oòrùn, tí ìsì mọlẹ dé iwọ oorun; bẹni wiwa Ọmọ-eniyan yíó rí pẹlu.” Matiu 24:27

Ọlọrun sọ ninu iwe Genesisi 11:6 pe gbogbo eniyan orile-ede ayé jẹ ọkan ati ede kan, èyí ní wọn sì bẹrẹ sí ní ṣe. Ko sí sí ohùn kan tí a o sí mú kúrò níwájú wọn tí wọn, ti wọn ti f’ọkan sí láti ṣe. Gbogbo ìwé tí a kà lapapọ da lé orí òpin ayé. Ọlọrun sí sọ pé kò ní sí ohùn tí a o gba kuro lọwọ wọn bi ìdènà fún aṣeyọri fún wọn, tí a bá fi wọn sílẹ. Ní ẹsẹ sẹ, ayé ntẹ̀siwaju lati tún jẹ́ ọ̀ kan ati èdè kàn, nípa ọna ẹrọ ayélujára, ọgbọn orí atọwọdọwọ ni wọn fí nkọ awọn ewe asiko yi ni ilé ẹkọ àwọn ọmọde, lati le jẹ ki ìmọ ṣe ọkàn: èyí wa fún wá ni àgbájọpọ káríayé. Èyí túmọ sí pé ohun tó bá nṣẹlẹ ní ibí kàn nínú ayé yíó di mímọ fún apá ibòmíràn ní iṣẹju kàn náà nínú ayé bakanna. Fún àpẹrẹ orin kikọ, iṣẹlu, aṣa ni oniruuru, Eniyan nwa bí yíó ṣe salà kúrò lọwọ iku bí a tí ṣe fí le’lẹ lati ọwọ Ọlọrun. Nitoripe ayé dàbí ọja, o sì tí di dandan pé gbogbo wá yíó padà sí ọdọ ẹlẹdà lati jihin iṣẹ wà. Ọlọrun sí sọkalẹ lati dá wọn ní èdè ru ki wọn tó tẹsiwaju. Bakanna bí gbogbo ayé tí ṣe ntẹsiwaju lẹsẹ lẹsẹ lati tun jẹ ọkan, ti wọn sì nwa orisirisi ọna nipa imọ lati takò ifẹ àti ìlànà Ọlọrun. Oluwa wà Jésù yíó yọ lawọ sanma, lakoko náà kìí ṣe lati dá èdè ru mọ, ṣugbon látì ṣe ìdájọ. Iwe Ìfihàn 22:12. Èyí jẹ àmì ìgbà ikẹhin, tí o nsọ fun wá n’ipa bibọ Kristi, nitori idi eyi a ní láti wà ní imurasilẹ.

ÁDÙRÁ
Olúwa nigbati o bá wá fẹ kó àwọn ènìyàn Rẹ, má jẹ́ kí ndi áwatí ni orukọ Jesu Àmín.
BIBELI KIKA: Genesisi 11:1-9

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *