Evils In Riches

THE SEED
“He that trusted in his riches shall fall; but the righteous shall flourish as a branch.” Proverb. 11:28 KJV

Yes, as children of God it is never a crime for us to be rich even our Father in Heaven has it in Abundance, that is why He said we should go into the world to multiply and be fruitful i.e. in all things we can think of. But when you are opportune to be wealthy do not intimidate the poor. God always give His Children Riches to be able to take care of the brethren [Body of Christ], his families [Immediate & distant] and everybody around that is less privileged, exactly
what the early Christian were doing sharing things among themselves in love none was noticed lacking anything or suffering. Having riches is not for pride, boasting, oppressing and self-centeredness. Like King Nebuchadnezzar that boasted before God had his body drenched with dew from Heaven turned to a beast and ate grass for good seven years, also the wicked Jezebel that used her power and richness to intimidate Nabboth it was dog that ate her corpse, we are implored to always be careful children of God, remember you only have today but tomorrow belongs to somebody else. All things however beautiful and ugly, big and small we acquire in this world is to remain here and nobody receives anything except being giving from Heaven, which means God is the owner of everything, we all have to watch it.

PRAYER
Oh Lord my God in your mercy you will always use me to bless others with all humility in Jesus Name. Amen

BIBLE READINGS: Proverb. 11

ÌBÍ TI O WÀ NÍNÚ ỌRỌ́
“Ẹnití o ba gbẹkẹle ọrọ̀ rẹ̀ yíó ṣubu: ṣugbọn olododo yio má gba bi ẹka igi.” Ìwé Òwe 11:28

Gẹgẹ bí ọmọ Ọlọrun kìí ṣe ẹsẹ láti ní ọrọ̀ , nitori pe bàbá wá tí nbẹ ní ọ̀run níí ní ọpọ yanturu. Nitori eyi ní O fí sọ pé kí a lọ sínú ayé kí a lọ bí síi kí a sí máa rẹ síi: èyi túmọ sí pé ninu ohun gbogbo ti a lérò làti lè ṣe réré. Tí o bá ní anfààní lati ni ọrọ, má fí pọn tálákà lójú. Ọlọrun máa n fún àwọn ọmọ Rẹ ní ọrọ nigbagbogbo lati le tọju awọn ará ninu Kristi, awọn ẹbí rẹ layika ati lọnà jijina rere ati gbogbo awọn ti o wà yíká ti o kú diẹ kàà to fún. Èyí ní àwọn Kristẹni akọkọ nṣe nipa ipinfunni laarin ará wọn nínú ìfẹ; kò sí ẹnití wọn ṣe àkíyèsí pé o ṣe àìní ohùn kàn, tàbí tí ìyà njẹ. Níní ọrọ kìí ṣe fún tí igberaga, ifunnu, ijẹgaba tàbí fún ìmọ tí ara ẹni nìkan. Gẹgẹ bí ọba Nebukadnessari ti o gberaga níwájú Ọlọrun, iri ọ̀run ṣe lè lórí; a sì yìí padà sí eranko, o sì jẹ
koríko fún ọdún méje. Bẹẹ gẹ́gẹ́ ni Jesebeli obirin búburú nì, ṣe ló agbara ati ọrọ̀ rẹ lati dẹruba Naboti; awọn ajá ní o jẹ òkú rẹ. A rọ wà láti jẹ ọmọ Ọlọrun tí o ní ìwà pẹlẹ, rántí pé iwọ lé ní ọjọ òní, ṣugbọn ẹlòmíràn lo ni ọjọ ọlá. Ohun gbogbo ti o rẹwa ati èyí tí kò rẹwa, yala o tóbi ati pe o kéré, tí a gbá nínú ayé yíó wá nínú ayé níbi, atí pé kò sí ẹnití o rí ohun kohun gba bi koṣe pe a fífún lati ọ̀run; èyí tí o túmọ sí pé Ọlọrun ní o ní ohùn gbogbo, a gbọdọ kiyesara.

ÁDÙRÁ
Oluwa Ọlọrun mí, nínú aanu Rẹ, ló mí nigbagbogbo láti bukun ẹlòmíràn pẹlú gbogbo ìrẹlẹ ni orúkọ Jésù Àmín.
BIBELI KIKA: Ìwé Òwe 11

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *