All Things Work Together

THE SEED
“And we know that all things work together for good to them that that love God, to them who are called according to his purpose.” Romans 8:28.

And we know that all things work together for good to them that that love God, to them who are called according to his purpose. Romans 8:28. Many people face challenges and tough times. One might be a believer or not. There will be times when it may be a good experience or the other way around. For a Christian, all the situation is orchestrated to bring us to a glorious ending. The understanding of the above scripture should make you know that all that you are going through as a child of God will all work out well. If you missed your car, it may be that God wants to protect you from an accident that would have happen. If you did not gain the admission to a university, it may be that the Lord wanted to protect you from being involved in the wrong relationship in that institution. This is a matter of trust. Having faith in God ‘s plan for you. You may not fully understand what is going on but you know that his plans are good to take you to an expected end.

PRAYER
I receive the power to trust you Lord that you are making everything to work for my favour in Jesus name. Amen.

BIBLE READINGS: Romans 8

OHUN GBOGBO ṢIṢE PỌ SÍ RÉRÉ

IRÚGBÌN NÁÀ
“Àwa sí mọ pe ohun gbogbo ṣiṣe pọ̀ sí réré fún àwọn tí o fẹ Ọlọrun, àní fún àwọn ẹnití a pè gẹgẹ bí ìpinnu Rẹ.” Romu 8:28

Àwa sí mọ pé ohun gbogbo ṣiṣe pọ fún réré fún àwọn tó fẹ Ọlọrun, fún àwọn ẹnití a pè gẹgẹ bí ìpinnu Rẹ. Romu 8:28. Ọpọ eniyan ní wọn ní idojukọ àti igba wahala. O le jẹ onígbàgbọ tàbí alaigbagbọ. Awọn igba miran wa tí o rọrun tabi idakeji. Fún Kristẹni, gbogbo idojukọ ni o parapọ̀ lati mú ògo ikẹhin wá. Óye nípa ẹkọ kika ti a ka sáà ju ni lati mu wá mọ pé ohun gbogbo ti a nlá kọ́ ja gẹgẹ bí ọmọ Ọlọrun yíó ṣiṣẹ pọ fún réré. Tí o bá pàdánù ọkọ ayọkẹlẹ rẹ o ṣee ṣe pé Ọlọrun fẹ fí pipadanu ọkọ bẹẹ ṣe ààbò fún ọ kuro nínú ìjàmbá ọkọ ti o fẹ ṣẹlẹ sí ọ. Tí o kò bá ní anfààní lati wọ Ile ẹkọ gíga, o lè jẹ́ pé a fí eyi dáàbò bọ ọ́ kúrò nínú dì dara pọ mọ awọn ẹgbẹ búburú. Tí o bá ní ìgbàgbọ nípa ètò Ọlọ́run fún ọ, o le má ní ẹkun rẹ rẹ ìmọ nípa òún ti o nlọ, ṣùgbọ́ n o mọ pé ètò Rẹ dára fún ọ láti mú ọ lọ sí igbẹhin réré.

ÁDÙRÁ
Mo gbà agbara lati gbẹkẹle Oluwa pe O nmu ohun gbogbo ki o ṣiṣẹ fún ojú rere mí ninu Jésù Àmín.

BIBELI KIKA: Romu 8

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *