THE SEED
“He who did not spare his own Son, but gave him up for us all—how will he not also, along with him, graciously give us all things?” Romans 8:32, NIV
Imagine getting up on Christmas morning and seeing a heap of presents under the tree yet never opening them. Imagine that your loved ones spent huge load of cash on you, getting you things you want that you cannot afford. Imagine that you even realize what was inside those bundles, however chose to allow them to sit under the tree every day of the week, a large number of years without touching them. After all, now you have what you’ve always dreamed of. You own whatever is in those boxes. If anyone asked, you’d say, “Yes, I have that.” But it wouldn’t do you any good because you would never be able to use those gifts unless you took the time to unwrap those packages. Friend, it’s the same way with God. He wants you to have an abundant life. His gifts are all right there for you wrapped up in the Word of God. You “open” His gift by meditating on His Word, obeying His commands and declaring it out of your mouth. Today, I encourage you to unwrap your gifts! Don’t let a single present sit “under the tree” any longer. Jesus paid a precious price so you could have both eternal life and abundant life. Unwrap your gifts and live in His fullness today!
PRAYER
Father, today I receive every good and perfect promise You have for me. I choose to take a step of faith to activate Your Word in my life. Teach me, by Your Spirit, to walk and live according to Your precepts in Jesus’ name. Amen.
BIBLE READINGS: Romans 8
TU ẸBÙN NÁÀ WÒ
IRÚGBÌN NÁÀ
“Ẹnití kò dá Ọmọ on tikararẹ̀ sí, ṣugbọn ti o jọwọ rẹ lọwọ fún gbogbo wa, yíó ha ti ṣe tí kì yíò fún wa li ohun gbogbo pẹlu rẹ̀ lọfẹ?” Romu 8:32
Ro o wò pé, ni jiji tí o ji ní owurọ̀ ọjọ Kérésìmesì, o rí ọpọ ẹbùn yanturu labẹ igi tí a kò tí ì tú wọn wò. Wa ro o ninu ọkan rẹ iye owo ti àwọn ololufẹ rẹ na fún ọ, ni fi fún ọ ní àwọn ohun tí o kò lè rí owó rà. Tilẹ ro pe o ní òye ohun tí a dì sínú àwọn ẹbùn wọn yí. O wá yan lati fún awọn ẹbun náà láàyè lati joko sí abẹ igi náà ni ọjọ jọ, ọ sọ sẹ, fún ọdún tó pọ̀ láì fí ọwọ kan awọn ẹbun wọnyi. O ṣa ti ní àwọn ohun tí o ti fí ọkàn dà nìyàn lati ni. Iwọ ní o sì ni àwọn ẹbùn tí a dì kalẹ. Tí ẹnikẹ́ni bá bí ọ lérè, o o sọ fún ẹni náà pé mo ní àwọn nkan wọnni. Sugbọn iru ìwà bayi kò lè é ṣe ọ ni anfani, nitori o kò ní lè lò awọn ẹbun wọnyi; a fí ti o bá wà Aaye lati tu awọn ẹbun náà. Ọrẹ bẹ gẹgẹ ní o rí pẹlu Ọlọrun. O fẹ, ki o ní ìyè lẹkun rẹrẹ. Awọn ẹbun Rẹ wá níbẹ fún ọ tí a fí
ọrọ Ọlọrun di. Tu àwọn ẹbùn wọnyi ki o sì máa ṣe àṣàrò ninu rẹ; máa gbọràn sí àwọn àṣẹ Rẹ, àti ki o sì máa sọ wọn jáde láti ẹnu rẹ. L’oni mo gba ọ níyànjú láti tù ẹbùn rẹ! Ma ṣe jẹ kí ẹbùn kankan joko sí abẹ igi mọ. Jésù sàn gbese iyebiye ki o ba lè ní ìyè àìnípẹkun àti iye lọpọlọpọ. Tu awọn ẹbun rẹ kí o sì máa gbé ninu ekunrẹrẹ iye.
ADURA
Mọ gbà awọn ileri ti o pé tí o sì dára, tí Ẹ ni fún mi. Mo yàn lati gbe ìgbésẹ ìgbàgbọ láti tun ọrọ Rẹ ṣe nínú ayé mi. Kọ mi nipa ẹ̀mi pẹlu ìlànà Rẹ. Ni orúkọ Jésù Àmín.
BIBELI KIKA: Romu 8