THE SEED
For to me to live is Christ, and to die is gain. Philippians 1:21
Paul the Apostle declares in the opening verse that Christ is the way to life. This means that the true meaning of life is to know, love, serve, exalt, enjoy, and be in communion with Christ. It implies that our primary goal in life is to come to know, worship, and enjoy Christ. It entails giving all of ourselves to Him in service to Him. It entails keeping a close eye on our words, deeds, and activities to make sure that they are exalting Christ. The knowledge that one day he would be with Christ, the desire to see others come to Christ, and an understanding of the cost of Christ’s salvation inspired Paul to live for Christ. Living for Christ is not to add to our justification; rather, it is to express our gratitude for the internal work the Lord has accomplished in us. The Christian should be recognised for leading an abundantly grateful life.As Christians, only Jesus Christ is worth living for. Nothing this world has to offer is superior to Jesus Christ. He personifies grace, mercy, wealth, honour, riches; glory, peace, joy, strength, love, rest, knowledge, health, healing, life, and finding Him is finding everything.
PRAYER
Father Lord in this New Year, help me to serve you more, know you more and dwell in your presence more. Amen
BIBLE READINGS: Philippians 1:20-22
GBÍGBÉ IGBE AYÉ FÚN JÉSÙ.
IRUGBIN NAA
Nitori niti èmi, láti wá lāye jẹ Kristi, láti kú jẹ èrè. Filippi 1:21
Paulu àpọsítélì fí hàn nínú ẹsẹ bíbélì tí a ka siwaju pé Kristi ní ọnà ìyè. Èyí túmọ sí pé ìgbé ayé tõtọ jẹ, mí mọ̀, ni ní ìfẹ, sí sìn, gbigbe ga, gbigbádùn ati wiwà ní ìdàpọ̀ pẹ̀lú Kristi. Ohun tí o jẹ akọkọ nínú ayé ní pe ki a wá lati mọ kristi, lati sìn àti láti wá ní irẹpọ pẹlú Rẹ. Ki a fí ará wá fún ùn nipa kí a máa sìn. Àní láti kíyèsi ọ̀rọ̀ ẹnu wà, iṣe wà ati ihuwasi wá kí a rí pé wọn gbé Kristi ga. A ni lati ri pe ní ọjọ kan a o wa pelu Kristi, àti kí a rí i pé àwọn ènìyàn wá sí ọdọ Krist. Òye ìgbàlà Kristi ru Paulu soke lati gbé ìgbé ayé fún Kristi. Gbígbé ayé fún Kristi kìí iṣe lati fi kun idalare wà; bikoṣepe lati fi rírí òòrè iṣẹ ti Kristi ṣe hàn fún wá. Kristeni gbọdọ ní idanimọ fún ìgbé ayé ọpẹ ni ẹkun rẹ rẹ . Gẹgẹ bí Kristẹni Jésù nìkan ni o l’ẹtọ sí kí ìgbé ayé wá, wà fún un. Kò sí ohun tí ayé yí lè fún wa ti o dára jù Jésù kristi lọ. Ore-ofe òun tikalararẹ, anu, ọrọ̀, iyi ọlá ati ògo, àlàáfíà, ayọ̀, ipá, ìfẹ, ifọkanbalẹ, ìmọ, ìlera, ìgbé ayé; wí wà Kristi rí túmọ sí wíwá ohungbogbo.
ADURA
Bàbá Oluwa wa, nínú ọdún tuntun yi, ran mi lọwọ láti sìn Ọ síi, lati mọ Ọ síi, ki emi sí leè máa gbé níwájú Rẹ síi. Amin.
BIBELI KIKA: Filippi 1:20-22