Abundant Life Today

THE SEED
“…I have come that they may have life, and that they may have it more abundantly.” John 10:10, NKJV

Is it safe to say that you are carrying on with the bountiful life Jesus came to give? His commitment of abundant life goes far past material things that this world offers. Abundant life signifies “life without limit.” That implies regardless of what is happening around you, you can participate in the full gifts of God. You can have peace in the midst of a storm. You can have joy when things are uncertain. You can have hope when circumstances seem hopeless. As believers,
a lot of times it’s easy to look at that verse and think, “God is going to give me abundant life someday.” But the truth is that God wants you to have abundant life TODAY! Don’t waste another second living in mediocrity or settling for less than God’s best. Receive His blessings by faith today. Receive His hope, joy, strength and favor. Declare that you are living the abundant life today and every day!

PRAYER
Father, thank You for sending Your Son, Jesus, so that I can have eternal life. I know that You want the best for me. Help me to keep my heart and mind focused on You so that I can walk in Your ways all the days of my life in Jesus’ name. Amen.
BIBLE READINGS: John 10

ÌYÈ LỌPỌLỌPỌ

IRÚGBÌN NÁÀ
“Èmí wá kí wọn lè ní ìyè, àní kí wọn lè ní í lọpọlọpọ” Jòhánù 10:10

Njẹ ààbò wà nínú iye lọpọlọpọ ti Jésù wá, láti fún ní? Ifi àrà ẹni jì, tí Jésù ní láti fún wá ni iye lọpọlọpọ, eyi pọ jù awọn ohun tí nbẹ nínú ayé lọ. Ìyè lọpọlọpọ túmọ sí “ayé tí kò ní odiwọn.” Eleyi jẹ wipe ohun kohun ti o wù kí o máa ṣẹlẹ ní àyíká rẹ, o le kopa lẹkun rẹrẹ ninu ẹbùn Ọlọrun. O lè ní àlàáfíà nínú ìji. O lè ní ayọ nigbati o kò ní ìdánilójú ohunkohun. O le ní ìrètí nigbati awọn wahala yọjú tí ìrètí rẹ gbogbo sí tí pin. Gẹgẹ bí onigbagbọ lọpọ ìgbà, lo rọrun lati wo ẹsẹ bíbélì kì a sì ronú nípa rẹ wipe; “Ọlọrun yíò fún mí ni ìyè lọpọlọpọ ní ọjọ kàn.” Otitọ tó wà níbẹ ní pe, Ọlọrun fẹ kí o ní ìyè lọpọlọpọ LONI! Ma fi iṣẹjù to kàn, ṣofo ninu gbígbé igbe ayé àtijọ, tàbí lati ni inu-didùn sí ohun tí Ọlọrun kò fẹ. Gbà ibukún Rẹ lọpọlọpọ lóni. Gbà ireti, gbà ayọ, agbara ati oju rere. Fihàn pé òun ngbe igbe aye ìyè lọpọlọpọ lóni ati ni ojojumọ.

ÁDÙRÁ
Olúwa, mo gba ìmísí rẹ pẹlu ìgbàgbọ, fún mi ni ìgboyà láti polongo ìhìnrere Rẹ lórúko Jesu. Amin.
BIBELI KIKA: Isaiah 40:9-11

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *