Be A Dream Releaser

THE SEED
‘Be devoted to one another in love…” Romans 12:10, NIV

Ponder on the people that God has set in your life. They’re not there unintentionally or by accident. God send people to you for a specific reason. We ought to live with this thought that “I am here to help and lift people. I’m here to assist them with succeeding.” Don’t go around continuously thinking, what help can the person do for you or what food can the person bring to the table for you or what they have to offer you. No, we should have the attitude, “What can I do for them? How can I help them come up higher? Can I teach them something I know? Can I connect them with someone who can help them?” Don’t make the mistake of going through life ingrown. Instead, be a dream releaser. Use your talent, your influence and your experience not just to accomplish your goals, but to help release a dream in someone else. Remember, there is nothing more rewarding than to lay down at night knowing that you helped someone else become better. You not only fulfilled your purpose for that day, you did your best. It may have just been a two-minute phone call where you encouraged someone; but when you
live as a dream releaser, you’ll see your own dreams come alive as well!

PRAYER
Father, show me ways to be a dream releaser and help others to rise up higher. Help me to use my influence to encourage others.
BIBLE READINGS: Romans 12

JẸ ẸNITÍ N FÍ ÈRÒNGBÀ ẸNÌKEJÌ HAN AN

IRÚGBÌN NÁÀ
“Niti ìfẹ ará, ẹ máa fi iyọnu fẹràn ará yín: niti ọla ẹ máa fi enikeji yín ṣaaju.” Romu 12:10

Ronú nípa àwọn ènìyàn tí Ọlọ́run gbé kalẹ fún ọ. Wọn ko sí níbẹ̀ là i nìdí, tàbí wọn ṣe ṣi wá sí iwájú rẹ. Ọlọrun rán àwọn ènìyàn sì ọ fún ìdí kan pato. A gbọdọ máa gbé pẹlú èrò yí pé ” Mọ wà níbí, láti ràn awọn eniyan lọwọ ati lati ru wọn sókè. Mo wa níbí láti mú wọn ṣe aṣeyege. Maṣe lọ kiri pẹlu èrò ọkàn pé kíní eniyan kan le ṣe fún ọ, irú onjẹ wò ni o le pèsè sori tábìlì rẹ, tabi kíní gán tí wọn lè ṣe fún ọ. Bẹẹ kọ, a ko gbọdọ̀ ni ero pé kíní mo le ṣé fún wọn. Bawo ni Mó ṣè le ran wọn lọwọ láti lè gòkè? Njẹ mo le kọ wọn ní ohun tí mo mọ? Tàbí mo le so wọn pọ mọ ẹnití mo mọ, kí o le ran wọn lọwọ? Ma ṣe aṣiṣe lati kọjá nínú ayé yí pẹlú èrò inú rẹ nikan ṣoṣo. Dipo eleyi, jẹ ẹnití o nfí èrò inú ẹlòmíràn hàn. Lo talẹnti rẹ, eniyan mi mọ rẹ, ìmọ rẹ, kìí ṣe fún iwọ nikan láti ṣe aṣeyọrí ninu ero ọkàn rẹ̀ sí réré: ṣugbọn lati le mú èròngba inú ẹlòmíràn ṣe. Rántí pé kò sí ohun tí o fún ní, ní èrè bíi kí pe ki o f’ara le’lẹ lẹhin iṣẹ oojọ; kí o sì ro o nínú ọkàn rẹ pé òun jẹ kí ènìyàn bíi tirẹ ṣe àṣeyọrí. Kìí ṣe pé o ṣe réré fún enikan ni ọjọ náà nìkan, o tún ṣe ìwọn ti o le ṣe. O le jẹ pé, o pè enikan lórí ẹrọ ibanisọrọ fún iṣẹju meji, lati gba irú ẹni bẹẹ níyànjú; ṣùgbọ́ n ni wọn ìgbàtí o bá ri ara rẹ ni ẹnití o nmu èrò ẹlòmíràn ṣẹ sí réré, iwọ yio ri pe ero ti iwọ náà yíó wá sí mi mú ṣẹ.

ÁDÙRÁ
Bàbá, ẹ fi hàn mí láti jẹ ẹnití yíó máà mú èrò inú ẹlòmíràn wá sí imúṣẹ sí réré àti láti jẹ kí ẹlòmíràn dé ibí gíga. Rán mí lọwọ láti lè lò ipò mí láti fi gba awọn miran ni yanju.
BIBELI KIKA: Romu 12

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *