Always Thank Him For Victory

THE SEED
“Now thanks be to God who always leads us in triumph in Christ” 2 Corinthians 2:14, NKJ

Isn’t it superb to realize that God vows to continuously lead us into victory? That implies regardless of what you are confronting today, regardless of what’s happening in your general surroundings, regardless of what anyone says, you ought to continuously be saying thanks to God since victory is consistently coming! You don’t have to wait for eveything to be perfect before you choose to celebrate what God will do in your life. Praise is putting action behind your faith. In the middle of that adversity or tough time, start making a list of who you’re going to invite to your victory celebration. That means if you’re in the hospital, start planning what you’re going to do when you get out. If you lost some money when the stock market went down, start planning your coming-out-of-debt party. When things don’t look good in the natural, remember, we serve a supernatural God. With God leading you into victory, you can always plan
for increase. You can plan for restoration. You can plan for a comeback, and you can plan for victory because He is leading and guiding you in Jesus’ name!

PRAYER
Heavenly Father, I give You thanks and praise today for the promise of victory. Give me Your vision for the future so that I can move confidently into the abundant life You have for me in Jesus’ name. Amen

BIBLE READINGS: 2 Corinthians 2

DUPẸ LỌWỌ RẸ NIGBAGBOGBO FUN ÌṢẸGUN

IRÚGBÌN NÁÀ
“Ṣùgbọ́ n ọpẹ ni fún Ọlọrun, ẹnití nyọ ayọ ìṣẹgun lórí wá nigbagbogbo nínú Kristi, tí o sì nfí õrun ìmọ rẹ hàn nípa wá nibigbogbo.” 2 Kọrinti 2:14

Njẹ ko jẹ iyalẹnu nlá wípé Ọlọrun ṣe ileri lati máa tọ wà sínú ìṣẹgun. Eleyi tumọ si pe láì bikita nipa ohun ti o nṣẹlẹ sí ọ loni, tabi ohun ti o nṣẹlẹ layika re, tabi ohunkohun ti o wù kí a sọ sí ọ. O nilo lati máà sọ fún Ọlọrun pe o ṣeun fún ìṣẹgun ìgbàgbogbo, O kò nilo lati dúró dé igbati ohun gbogbo ba wa ni deede kí o tó ṣe ajoyọ ohun ti Ọlọrun yio ṣe fún ọ. Ìyìn l’ogo jẹ fífi ojúṣe kẹhìn ìgbàgbọ. Ni arin idaamu àti wahala bẹrẹ sí ní ṣe akọsilẹ iye awọn ti yíó wá bá ọ ṣe ajoyọ ìṣẹgun rẹ. Èyí jẹ wipe ti o bá wá ni idubulẹ àìsàn ní ilé ìwòsan bẹrẹ sí ní ṣe ètò ohun ti o o ṣe tí o bá jáde kúrò ní ibẹ. Tí o bá pàdánù owo nigbati òwò rẹ kò lọ dédé, máa ṣe igbaradi láti bọ kúrò nínú gbèsè. Nigbati nkan ko ba lọ dédé lójú ayé rántí pé a nsìn Ọlọrun oke ti a kò rí. Pẹlu Itọni Ọlọrun, sinu ìṣẹgun o le bẹrẹ sí la ọna lati ní ẹkùn rẹrẹ ibukun. O le ṣètò fún imu dúró. O le ṣètò fún ipadabọ, àti ètò fún ìṣẹgun nítorí O n fún ọ ní ìlànà ati itọni ninu Jesu.

ÁDÙRÁ
Bàbá wá ọrùn mo dúpẹ mo yín Ọ fún ìlérí ìṣẹgun. Fún mí ní ìran Rẹ ọjọ iwájú ki èmi kì o le rìn pẹlu igboya wọ inú ọpọlọpọ ìyè ti O ní fún mí ni orúkọ Jésù Àmín.
BIBELI KIKA: 2 Korinti 2

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *