Seek The Lord

THE SEED
“I sought the LORD, and he answered me; he delivered me from all my fears.” Psalm 34:4, NIV

Nowadays, it appears to be that there are such countless things that individuals fear. I’m not simply discussing fears. Many individuals fear the future, apprehensive they will not get hitched, apprehensive they won’t get a superior line of work, scared of becoming ill. Yet, the bible gives us a basic solution for every of our fear, and that is, to look for the Lord. How do you seek the Lord? With a humble and open heart. By setting aside time each day to commune with Him. By focusing your thoughts on Him and His goodness. Friend, no matter what fears may be plaguing your mind today, God wants to deliver you. He promises to keep us in perfect peace when we keep our minds stayed on Him. Today, meditate on His goodness. Meditate on His perfect love which casts out all fear. As you seek the Lord, He will answer you. He will deliver you and lead you in the path of peace and victory all the days of your life!

PRAYER
Father, thank You for Your faithfulness to me in every area of my life. Thank You for delivering me from all my fears. Help me keep my mind and heart fixed on You as I reach out to embrace the good things You have in store for me in Jesus’ name. Amen.

BIBLE READINGS: Psalm 34

WÍWÁ ỌLỌRUN

IRÚGBÌN NÁÀ
“Èmí ṣe afẹri Oluwa, O fí etí simi; O sí gbà mí kúrò nínú gbogbo ìbẹrù mi.” Psalmu 34:4

Lóde òní a ri wipe ọpọ awọn nkan ni awọn eniyan bẹrù. Nko sọ nípa ẹrú, ọpọ eniyan ló bẹrù ọjọ iwájú, wọn ní ipaya wípé wọn yíó wọ wahala, ìbẹrù bojo bóyá wọn kò ní rí iṣẹ ti yíó tán iṣẹ. Ìgbé lọkàn soke nípa ṣíṣe àìsàn. Sibẹ Bíbélì fún wa ni ọna abayọ fún ìbẹrù wá kọkan, èyí ni lati wá Oluwa. Báwo ní o o ṣe wá Olúwa? Pẹlu irẹlẹ ati ọkan tí o ṣipaya, nipa fifi ayé silẹ ni ojojumọ láti bàa sọrọ. Nipa ka ní ifojusi èrò wà nipa Ọlọrun àti ìre Rẹ. Lóni ṣe àṣàrò lórí ìre Rẹ. Ṣe àṣàrò lórí ìfẹ Rẹ ti o pé, ti o sì nlé ẹrú jade. Bi o ti ṣe nwa Oluwa, yíó dá ọ lóhùn. Yíó tu ọ silẹ, yíó tọ ọ sí ọnà alaafia ati ìṣẹgun ni gbogbo ọjọ ayé rẹ.

ÁDÙRÁ
Baba Mo dupẹ fún ijolotitọ yín ní gbogbo ọnà ayé mí. Mo dupẹ fún itusilẹ mi kúrò ninu ìbẹrù. Rán mí lọwọ láti lè gbé ọkàn mi ati àyà mí lé Ọ, bí mó ti ṣe nwa lati gba awọn ohun tí o dara, tí O ní ní ipamọ fún mi, ni orúkọ Jésù Àmín.

BIBELI KIKA: Psalmu 34

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *