A Supernatural Encounter

THE SEED
“But we all, with unveiled face, beholding as in a mirror the glory of the Lord, are being transformed into the same image from glory to glory, just as by the Spirit of the Lord.” 2 Corinthians 3:18, NKJV

A rare most astounding change in the Bible happened when Saul — previous persecutor of Christians — experienced God on his way toward Damascus (see Acts 9). After his experience, he was so fundamentally different from inside out that even his name was changed to Paul. He started teaching the gospel, and at last, proceeded to compose a significant part of the New Testament. When you have a supernatural encounter with Almighty God, something is going to happen. Something is going to be transformed inside of you and radiate out into every part of your being, affecting every part of your life! Today, I want to encourage you to prepare your heart to expect God’s supernatural touch in your life. Open the eyes of your heart to Him. I pray that you experience God in such a way that every bondage is broken off of your life, and you are forever changed by a supernatural encounter with Him!

PRAYER
Father, right now I invite You to transform me into Your image. Search my heart and mind and remove anything that is displeasing to You. Show me Your glory. Reveal Yourself to me as I keep my heart and mind focused on You in Jesus’ name. Amen.

BIBLE READINGS: Act 9

ÌBÁPÀDÉ AT’OKE WA

IRÚGBÌN NÁÀ
“Ṣugbọn gbogbo wa nwò ògo Oluwa láìsí iboju bí ẹnipe nínú awojiji, a sì npawada sí aworan kànnà lati ògo dé ògo àní bí lati ọdọ Oluwa tí iṣe Ẹ̀mi.” 2 Kọrinti 3:11

Agbayanu iyipada ti kò wọpọ ṣẹlẹ nínú Bíbélì – ẹnití o jẹ awọn kristeni ni ìyá ṣe ibapade Ọlọrun ní ojú ọnà Damasiku (Iṣe Àpọsítélì Orí kẹsán). Lẹhin iriri, ho ni iyipada to jinlẹ̀ to bẹẹ gẹ ti a nilati fi yi orúkọ rẹ pàdà sí Paulu. O bẹrẹ sí kọni lẹkọ ìhìnrere, lẹhin èyí o wá bẹrẹ sí ní kọ́ apakan ninu iwe Majẹmu Titun. Nigbati o bá ní ìrírí ibapade atoke wa pẹlu Ọlọrun alagbara, ohun kan yíó wá ṣẹlẹ. A o yi ohun kan padà nínú rẹ tí yíó tan jáde sí gbogbo ẹyà ará rẹ, ti yíó ní ṣe pẹlú ìgbé ayé rẹ. Loni, mo fẹ gba ọ níyànjú láti gbaradi ninu ọkan rẹ lati ni ìrètí lat’ọdọ Ọlọrun fún ifọwọkan atoke wa ninu ayé rẹ. Ṣi ojú ọ̀ kan rẹ fún ùn. Mo gbàdúrà kí o le ní iriri pẹlu Ọlọrun, ni ọnà tí àwọn àjàgà inu ayé rẹ yíó fí dì gígé kúrò; ti iwọ o fí ní ibapade atoke wa pẹlu Ọlọrun titi lai.

ÁDÙRÁ
Bàbá láti isisiyi lọ, mo pé Ọ, lati wá yí ayé mi padà sí aworan ara rẹ. Wa sinu ọkan mí ati aya mí, kí o si mú ohun tí kò tẹ Ọ lọrùn kúrò. Fí ogo Rẹ̀ hàn mí. Fi ará Rẹ hàn fún mí bí mo ṣe n tẹ lé Ọ ní orúkọ Jésù Àmín.

BIBELI KIKA: Iṣe Àpọsítélì 9

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *