Giving Is Worship

THE SEED
“And on going into the house, they saw the Child with Mary His mother, and they fell down and worshiped Him. Then opening their treasure bags, they presented to Him gifts..” Matthew 2:11, AMP

At the point when the wise men originally saw Jesus, they were totally overwhelmed. They tumbled to their knees and needed to worship Him with all that they had. Giving was a programmed reaction. They needed to pamper Him with their affection and gifts. They were giving because they were thankful and needed to respect Him. When you give to God, He doesn’t want you to do it just because it’s offering time or because you feel like you have to. In fact, the Bible says, “Do not give grudgingly or under compulsion.” God wants you to give because your heart is overflowing with thankfulness. He wants you to be happy and cheerful
when you give. He loves a cheerful giver! Meditate on the faithfulness of God today. Think about what He’s done for you—that He’s saved and redeemed You. Dwell on the fact that He is your provider. As you meditate on His goodness, your heart will overflow with thankfulness, and just like the wise men, giving will be an automatic response!

PRAYER
Father, I choose to meditate on Your goodness today. Thank You for loving and saving me. Thank You for redeeming my life from the pit. I give You everything that I am today in Jesus’ name. Amen.
BIBLE READINGS: Matthew 2

 FIFUNNI JẸ ÌSÌN

IRÚGBÌN NÁÀ
“Nigbati nwon sí wọ Ile nwọn ri ọmọ ọwọ naa pẹlu Maria iya rẹ, nwọn wolẹ, nwọn sí foribalẹ fún u: nigbati nwọn sí tu ìṣura wọn, nwọn tá a lọrẹ wura, ati turari, ati òjíá.” MATIU 2:11

Nigbati awọn amòye ri Jesu, wọn ni iyanu nla. Wọn wolẹ lori eekun wọn lati juba rẹ pẹlu ohun gbogbo ti wọn ni. Fifunni jẹ ìṣe ti a la kalẹ. Wọn nilo lati kẹ ẹ pẹlu ìfẹ àti àwọn ẹbùn. Wọn fifunni nitori pe wọn jẹ ọlọpẹ, wọn sí nilo lati bù ọlá fún ùn. Nigbati o bá fifun Ọlọrun, kò fẹ kí o ṣe bẹẹ nitori pe o jẹ àsìkò ọrẹ tàbí o lero pe o wun ọ lati ṣe bẹẹ. Bíbélì tilẹ sọ pé “ki iṣe àfèkùnṣe, tàbí alaigbọdọ má ṣe”. Ọlọrun fẹ kí o fún ní nítorí ọkàn rẹ kún àkúnwọsílẹ fún ọpẹ. O fẹ ki o kí o ní ayọ àti inudidùn, ti o bá mú ọrẹ rẹ wá. O fẹràn oninu didun ọlọrẹ! Ṣe àṣàrò lórí otitọ Ọlọrun loni. Ro nípa ohun tí o ti ṣe fún ọ. O gbà Ọ la, O ra ọ pada. Dúró lórí otitọ pe O npe se fún ọ. Bí o ti ṣe nṣe àṣaro lórí ìre Rẹ, ọkàn rẹ kun àkúnwọsílẹ fún ọpẹ, gẹgẹ bí àwọn amòye mẹta, fifunni ni lati jẹ ohun a i ronú ṣe.

ÁDÙRÁ
Mo yàn láti ṣe àṣàrò lórí ìre Rẹ loni. Modupe fún ìfẹ igbala Rẹ fun mí. Mo dupẹ fún ìràpadà ayé mí kúrò nínú koto. Mo fún Ọ ní ohun gbogbo ti mo jẹ loni ni orúkọ Jésù Àmín.

BIBELI KIKA: Matiu 2

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *