The Ultimate Gift

THE SEED
For unto us a child is born, unto us a son is given: and the government shall be upon his shoulder: and his name shall be called Wonderful, Counselor, The mighty God, The everlasting Father, The Prince of Peace.” Isaiah 9:6, KJV

What a wonderful gift the Father has given us by sending His Son, Jesus, the Prince of Peace, into the earth! Because of Him, all those who believe can have peace with God and make heaven their home. But not only did the Prince of Peace open the way to go to heaven, He made it possible to have peace on earth—every day in every circumstance. Today, we declare peace over you and your home. We celebrate with you the greatest gift of all—Jesus Christ! If you don’t know this peace that the Father so freely gives, open your heart and invite Jesus to make your heart His home. He is the ultimate gift! Merry Christmas from The Primate, Her Eminence The Most Revd. Dr. Mrs. Olufunke Babayemi JP (Iya-Ewe) to you and your household.

PRAYER
Father, thank You for the gift of Your Son, Jesus Christ. Today I open my heart and mind to You and declare that Jesus is Lord over me. Fill me with Your peace and joy as I keep my mind stayed on You in Jesus’ name! Amen.

BIBLE READINGS: Isaiah 9

ỌRẸ IKẸHIN

IRÚGBÌN NÁÀ
“Nitori a bí ọmọ kan fún wa, a fi ọmọkùnrin kan fún wa; ijoba yíó sí wa li ejika rẹ; a o sì ma a pe orukọ rẹ ni ìyanu, oludamọran, Ọlọrun Alagbara, Bàbá Ayérayé, Ọmọ Aládé Alaafia.” Isaiah 9:6

Irú agbayanu ọrẹ tí Bàbá fún wa nipa fifi ọmọ Rẹ ranṣẹ sí wa, Jésù tí nṣe ọmọ aládé àlàáfíà, sinu aye. Nitori tirẹ̀, gbogbo awọn ti o gbagbọ lè ní àlàáfíà pẹlú Ọlọrun àti ki wọn le fí ọrun ṣe ibùgbé wọn. Kì í ṣe pé ọmọ aládé àlàáfíà ṣí ọnà ati lọ sí ọrùn nikan, O jẹki o ṣe e ṣe lati ni àlàáfíà ninu ayé – ní ojojumọ ninu gbogbo ayidayida tí a nlá kọja. Loni, a tú alaafia sí orí rẹ àti ilé rẹ pẹlú, A sí tun bá ọ ṣe ajọyọ pẹlú ẹbùn nla julọ tí nṣe Jésù kristi! Tí o ko ba mọ irú alaafia ti Ọlọrun fún ọ lọfẹ, ṣí ọkàn rẹ paya pe, Jesu wọle sínú ọkàn rẹ lati fi ibẹ ṣe ilé. Òun ni òòrè ikẹhin. Ìkíni kú ọdún kérésìmesì sí ọ àti àwọn ará ilẹ rẹ, wá láti ọdọ Olùdásílẹ̀, ọlọlá julọ, woli àgba, Dókítà, ìyá àfín Olufunke Bàbáyẹmi JP Iya Ewe.

ÁDÙRÁ
Bàbá Ẹ ṣeun fún ẹbùn yín tí nṣe Jésù kristi ọmọ yín, Loni mo ṣí ọkàn mi ati aya mí sílẹ̀ fún Ọ́ mo sí jẹwọ pe Jesu ní Oluwa lori mi. Kún mi pẹlú àlàáfíà àti ayọ bí ọkan mi ṣe nsin mi lé ọ ní orúkọ Jésù Àmín.

BIBELI KIKA: Isaya 9

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *