You Are Highly Favored!

THE SEED
“The angel went to her and said, “Greetings, you who are highly favored! The Lord is with you.” Luke 1:28, NIV

Did you have any idea that as a child of God, you are highly favored? Regardless of what you might have done previously, when you make Jesus Christ your Lord and Savior, you have favor with God! Mary didn’t understand how or why she had God’s favor, or what that favor was for. At that moment, she didn’t know that she was chosen as a pure and holy vessel to bring Christ to the world. Friend, you have God’s favor for the very same reason as Mary – because God chose you and made you a pure and holy vessel to bring Christ to your home, workplace, and even the world. Stay focused on sharing the message of God’s love with all those you come in contact with. And remember that today, and every day, you are highly favored and the Lord is with you!

PRAYER
God, I have an awesome responsibility to share Your message with the world. It is my gift to You to embrace that calling.

BIBLE READINGS: Luke 1

IWỌ NÍ OJU-RERE TI O GA

IRÚGBÌN NÁÀ
“Angẹli náà sì tọ ọ wá, o ní, alaafia iwọ ẹnití a kọ oju sí ṣe lóore, Olúwa pẹlú rẹ,” Luku 1:28

Njẹ o tilẹ loye wipe gẹgẹ bí ọmọ Ọlọrun o ní ojurere to ga? La i rántí àwọn ohun atẹhinwa tí o tí ṣe; nigbati iwọ fí Jésù Kristi ṣe Olùwà àti Olùgbàlà rẹ: o ni oju-rere pẹlú Ọlọrun. Maria kò ní òye tàbí èrè ìdí tí o fí ni oju-rere láti ọdọ Ọlọrun, tàbí ohun ti oju-rere vyi tumọsi. Lakoko naa, kò mọ pe a yàn oun bi ohun èlò tí kò l’abawọn tí o sì jẹ mimọ, láti mú Kristi wá sí ayé. Ọrẹ, o ni oju-rere Ọlọrun gẹgẹ bí tí Màríà; nitori pe Ọlọrun yan ọ bí ohun èlò alailabawon àti mímọ lati mu Kristi wọ Ile rẹ, ibí iṣẹ ati paapa julọ wá sínú ayé. Gbiyanju lati ní afojusun ki o lè royin ifẹ Ọlọrun fún àwọn tí o nbá pàdé. Rántí pé loni, ati ni ojoojumọ, o ní ojú réré to ga àti pé Olúwa wa pẹlu rẹ.

ÁDÙRÁ
Ọlọrun mo ní ojúṣe agbayanu lati ròhin iṣẹ Rẹ fun agbaye. O jẹ ẹbùn fún ọ gbà irú ìpè bẹẹ. Ni orúkọ Jésù Àmín.
BIBELI KIKA: Luku 1

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *