THE SEED
And the LORD went before them by day in a pillar of a cloud, to lead them the way; and by night in a pillar of fire, to give them light; to go by day and night: Exodus 13:21
The Israelites were reminded of God’s presence in their life by the pillars of cloud and fire. They are being led by these enormous pillars, which give them the freedom to move at any hour of the day and never leave them. God’s influence is palpable and genuine. Therefore, God never abandoned them. We serve a God who never deserts his people. He provided His people with light, truth, and direction through the pillar of cloud and fire. God wants to lead us like a shepherd would his flock, not as a magician would perform tricks on a bewildered audience. His Word has nothing to say about topics that primarily pique our curiosity because He wants to offer us His life, but instead focuses on the intellect, understanding, and heart. God desires to guide us into a deeper life of faith and power, reveal His thoughts to us, and make known His presence through the things He accomplishes through us every day, the salvation of souls around us, the crushing of haughty and sinful hearts, the opening of heathen nations to the Gospel, the working of His providence in the events of our time, the evangelization of the world, and these mighty overturnings which are to bring the glorification of His Son.
PRAYER
Order my step, oh Lord. Let me not go astray.
BIBLE READINGS: Exodus 13:1-21
ỌWỌN ÀWỌSÁNMÀ ATÍ INA
IRUGBIN NAA
Oluwa sí nlọ níwájú wọn, nínú ọwọn àwọsánmà li ọsan, lati máà ṣe amọna fún wọn; ati li oru li ọwọ̀n iná lati máà fí imọlẹ fún fún wọn; lati máà rìn li ọsán ati li oru – Eksodu 13:21
A rán àwọn ọmọ Israẹli létí iwalaaye Ọlọrun ninu ayé wọn; nipa ọwọn àwọsánmà ati iná. A dárí wọn nipa awọn ọwọn nla yi, ti o fún wọn ní ààyè lati rìn ninu awọn wakati ọjọ ti wọn kò sí fí wọn sílẹ. Ipa Ọlọrun jẹ ojúlówó àti òtítọ. Nitorina Ọlọrun kò kọ̀ wọn sílẹ. A nsìn Ọlọrun tí kò kọ́ àwọn ènìyàn rẹ̀ sílẹ̀ láé. Ẹnití tí ó pèsè ìmọ́lẹ̀, òtítọ́, àti ìdarí fún àwọn ènìyàn Rẹ̀ nípasẹ̀ ọ̀wọ̀n àwọsánmà àti iná. Ọlọ́run fẹ́ láti ṣamọ̀nà wa bí olùṣọ́ àgùntàn ṣe máa ń ṣe amọ̀na agbo ẹran rẹ̀, kì í ṣe gẹ́gẹ́ bí pidánpidán ṣe máa ń tan àwọn olùgbọ́, tí wọ́n ní ìdààmú jẹ. Ìpinu Ọlọrun ni lati tọ́ wá sí ọ̀nà ìgbàgbọ àti agbára tí o jinlẹ̀ àti láti jẹ kí a mọ èrò rẹ sì wà. Lati jẹ kí a mọ iwalaaye Rẹ nipa ohun ti o ngbe ṣe ninu ayé wa lojojumọ. Fún àpẹrẹ, igbala awọn ọkan ni àyíká wà, wíwó ojú ìgbéraga àti ọkàn ẹṣẹ palẹ, li lá ọnà fún ihinrere ní ilẹ̀ àwọn keferi, iṣẹ itọju Rẹ ninu awọn igba ati akoko wà, ipolongo ihinrere fún gbogbo ayé; gbogbo agbé kalẹ nla ti Ọlọrun ṣe wọnyi wà fún iṣelogo Ọmọ Rẹ.
ADURA
Tọ iṣisẹ mi Oluwa, ma ṣe jẹ kí nṣina.
BIBELI KIKA: Eksodu 13:1-21