The Crown Of Life

THE SEED
Blessed is the man that endureth temptation: for when he is tried, he shall receive the crown of life, which the Lord hath promised to them that love him. James 1:12

It is difficult, if not impossible, to expect Christians to maintain their faith in a society that has been fully trained to demand quick fulfilment. According to the introductory verse, Christians will get various benefits, including those for withstanding temptation. Some Christians might be surprised by this, but the Bible does not contain any lies, so it must be true. But difficulties and trials are not the only aspects of the Christian life. God is aware of our trials and promises to turn them to our advantage and the glory of Himself. When the difficulties are through, God will show His satisfaction with us by rewarding us for maintaining our resolve during the ordeal. You will undoubtedly be required to endure difficulties as a Christian, both material and spiritual. Every life experiences difficulties and trials; no one is exempt. This verse should motivate Christians who are facing temptation to persevere through it in order to win the crown of life. Christians who endure temptation to the very end demonstrate their love for Christ in addition to gaining the crown of life. You will face temptation as a test of your love, and you must persevere through it to receive the crown of life.

PRAYER

Father give me an enduring faith that can withstand all storms.

BIBLE READINGS: James 1

ADE ÌYÈ

IRUGBIN NAA
Ibukún ni fún ọ̀kunrin ti o fi ọkàn rán ìdánwò: nitori nigba ti o bá yege, yíó gbà adé ìyè, ti Olúwa tí ṣe ileri fún àwọn tí o fẹẹ. Jakọbu 1:12

O jẹ ohun ti o ṣòro, tàbí tí a lè sọ pé kò lè ṣéé ṣe fún Kristẹni láti mú kí ìgbàgbọ wọn fẹsẹ mú lẹ larin awujọ ti o gbé ọkàn soke lati mu ohungbogbo wá sí imuṣe ni kánkan. Gẹgẹbi ẹ́sẹ to ṣaájú Kristiẹni yíó gba ere oriṣiriṣi pẹlú eleyii ti o wá fún iforiti nínú wàhálà. O lè ya awọn kristeni kàn lẹnu nipa eleyi, ṣùgbọ́n bíbélì kò gba irọ pipa láàyè, nitori idí èyí otitọ ni. Ìṣòro àti àdánwò nikan kọ ní o jẹ ipa ọnà ìgbé ayé kristeni. Ọ́lọ́run mọ nípa ìdánwò ati ileri wà, lati yi wọn pada sí ànfààní ati ògo ati ògo ara Rẹ. Nigbati awọn iṣoro wọnyi ba dopin, Ọlọrun yíó fí ìyọnu hàn sí wà nipa fifun wa ni ere nitori ìdúróṣinṣin wa lati yanju ìṣòro. Lá i ṣe iyemeji o jẹ aigbọdọ ma ṣè fún Kristiẹni lati fàya ran ìṣòro yala nipa tí ohun ini tabi ẹmi. Ninu awọn iriri aye, ko sí ẹni tí a yọ silẹ kuro ninu wàhálà ati idanwo. Ẹsẹ bíbélì yi jẹ ohun ti yíó mú Kristẹni tí o ba ndojukọ wàhálà, fi àyà rán ìṣòro lati le gba adé ìyè. Awọn kristeni ti o ba fi ará da ìdánwò titi dé òpin nfi ifẹ wọn han sí Kristi. Ni afikún lati gba adé ìyè. Iwọ yíó dojukọ adanwo èyí jẹ́ ìdánwò ìfẹ rẹ fún Kristi, o sí gbọdọ fi àyà rán an lati
gba adé ìyè.

ADURA
Bàbá fún mi ni igbagbọ tí o nfi aya rẹ ìṣòro, ki emi ki o le kọ ojú sí ìjì. Àmìn.

BIBELI KIKA: Jakobu 1-ipari

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *