Demonstrate Your Thanks

THE SEED
In everything give thanks for this opportunity is the will of God in Christ Jesus for you. 1 Thess 5:18

Demonstrate your thanks to God in all He gave and done for you with all the part of your body, e.g. mouths, feet, arms etc. David said, “Bless the Lord, O my soul and all that is within me, bless His Holy name Psalm 103 vs 1. This is the will of God to all who are called by Him; to praise the Holy one inhabits in the praises of His people. Psalm 22:3 The demonstration shows how grateful we are and how much we love our Lord Jesus Christ. If it’s difficult for you to show your gratitude to Him then you need to examine yourself if He’s your Lord and Saviour.

PRAYER
Father, help us to always praise and demonstrate our thanks to you
BIBLE READINGS:  Psalm 95:1-11

FI OPE RE HAN

IRUGBIN NAA
E máa dupe ninu oun gbogbo nitori eyi ni ife Olorun nipa Kristi Jesu fun yin. 2 Tesalonika 5:18

Fi ope re han si Oluwa pelu oun gbogbo ti o wa ni ara re fun oun ti O se fun o. Dafidi wipe “Fi ibukun fun Oluwa, iwo okan mi ati oun gbogbo ti o wa ninu mi, yin oruko Re mimo” Orin Dafidi 103 vs 1. Eyi ni ife Olorun fun awon to O pè; lati yin eni mimo ti o gunwa ninu iyin awon eniyan Re. Orin Dafidi 22 vs 3. Sise afihan ope wa máa n so bi a se m’ore Oluwa to ati bi a se ni ife Oluwa wa Jesu Kristi. Ti ó ba nira fun o lati fi emi imoore han, a je wipe o ni lati ye ara re wò boya Oun ni Olorun re ati Olugbala re.

ADURA
Baba wa, je ki a le máa yin o, ki a si máa se afihan ope wa si O. Amin.
BIBELI KIKA: Orin Dafidi 95 vs 1-11

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *