Thanking God Is My Choice

THE SEED
I will bless the Lord at all times His praise shall be to my mouth. Psalm 34:1

My choice is thanksgiving because thankful people choose to focus on the positive things the Lord has done for them and not the negative. They find ways of turning negatives into positives knowing that God make everything to work for their good. James 1vs2 The furnace may be uncomfortable but the product is beautiful Romans 8 vs 28 The thankful is always looking for the best in world around them and often find exactly what they want in Christ. Psalm 8 vs 3-4. The choice we make goes a long way in how we receive more from God. Know that your situations will not change God. He remains God in spite of your situations. He can change all situations but nothing changes Him. The choices of thanking Him always can be all the difference you need in your situation. What a great way of changing our lives in thanksgiving make up your mind.

PRAYER
Father your praises will not stop in my mouth.
BIBLE READINGS:  Psalms 19:1-14

   DIDUPE NI OWO OLORUN NI MO YAN

IRUGBIN NAA
Emi yio fi Ibukun fun Olowa nigbagbogbo, iyin Re yio ma w ani enu mi. Orin Dafidi 34:1

Mo yàn lati máa dupe ni owo Olorun nitori pe awon to ba je olope máa n fojú si ohun rere ti Oluwa se fun won. Iru awon béè máa n wa ona lati yi ero buburu si rere nitori won mo wipe Olorun a máa mu ki ohun gbogbo  yori si rere fun won. Romu 8 vs 28. Ipo ti o wa leè gbona sugbon igbeyin re a dara. Jakobu 1 vs 2-3. Eni ti o ni ope máa n wá oun ti o dara ninu aye, a si rí oun ti o fe ninu Kristi. Orin Dafidi 8 vs 3-4. Ohun ti a bá yan máa n so bi a se le gba ni owo Olorun. Mọ daju wipe ipo re, ko le yi Olorun ni ipo pada. Olorun ni yio ma je. Ó ni agbara lati yi ipo re pada, sugbon a ko le yíi n’ipo pada. Yíyàn lati dupe ni owo rè le je oun ti yio mu ayipada rere ba o. Se ipinu rere l’oni.

ADURA
Baba mi, iyin re koni tan ni enu mi. Amin.
BIBELI KIKA: Orin Dafidi 19: 1-14

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *