From Goodness Comes Good Reward

THE SEED
“As we have therefore opportunity, let us do good unto all men, especially unto them who are of the household of faith.” Galatians 6:10

As the usual saying goes, whoever does good, will receive goodness and vice versa. There was a man of God that usually pass by a woman’s house, she and her husband were always nice to him. It got to a stage that the woman pleaded with her husband to let them make a room for the man because she perceived he was a man of God. The husband agreed and whenever the man of God comes around, he has a comfortable room to himself. The man was surprised by her hospitality. Despite her wealth and riches, she was not swollen-headed or arrogant, but respectful, calm, nice and accommodating. He started to wonder what he could do for the woman to repay her for all her good attitudes towards him. She was asked if she needed anything but she said she has everything she wanted. However, the servant to the man of God noticed that they have never met a child there since they have been coming there. The Man of God then prophesied that by the time he comes again in a year’s time she would have a baby boy. Though she doubted him but God made it to come to pass. So, wherever we go, let us be good in line with the good behavior of our Lord Jesus Christ because the Bible says, everywhere He went, He was doing good.

BIBLE READING: 2 Kings 4:8-17

PRAYER: My Father, I pray let me not bring shame to your name but to always do good wherever I go.

NINU SISE RERE NI ESAN RERE WA

IRUGBIN NAA
Nítorí náà bí a ti ní àǹfààní, ẹ je kí a máa ṣe rere sí gbogbo ènìyàn, pàápàá fún àwọn tí í ṣe ti agbo ilé ìgbàgbo. Galatia. 6:10.

Gege bí oro ti awon ènìyàn maa n so ” ẹni tí ó bá ṣe rere, yóò gba esan rere, eniba si se buburu, yio gba esan buburu”. Ènìyàn Ọlorun kan wa ti o maa n gba ile obinrin kan koja, oun ati oko re ni won maa n Wu iwa daradara si. Óbìnrin náà bẹ ọkọ re pé kó jekí won ṣe yàrá fún ọkùnrin náà torí ó mo pé èèyàn Ọlorun ni. Ọkọ gba ati pe nigbakugba ti eniyan Ọlọrun ba wa ni ayika, o ni yara itura fun ara rẹ. Ẹnu yà ọkùnrin náà nípa iwa ikonimora won. Botile je wipe, obirin naa je Oloro pupo, ko ni igberaga, ṣugbọn o je onirele, enitutu, o si ko ènìyàn mora.Iranse Ọlorun na a bere SI ro oun to le se Lati San iwa rere ti arabinrin náà wu si. O beere boya o nilo ohunkohun ṣugbọn arabinrin naa da lohun pe oun ko Fe ohunkohun. Iranse Ọlorun náà ṣàkíyèsí pé àwọn kò tí ì bá ọmọdé kankan rí níbe láti ìgbà tí o ti n was síbe. Ènìyàn Ọlorun náà sọ tele pé nígbà tí òun bá tún pada wa lehin odun kan SI, won yio ti bi omokunrin kan. Bí ó tile je pé ó ṣiyèméjì sùgbon Ọlọrun mú kí ó ṣẹ. Nítorí náà, ibikíbi tí a bá lọ, ẹ je kí a je ẹni rere ní ìbámu pelú ìwà rere Oluwa wa Jesu Kristi nítorí pé Bibeli sọ pé, níbi gbogbo tí ó bá lọ, ó ń ṣe rere.

BIBELI KIKA: IWE AWON OBA KEJI. 4:8-17

ADURA: Baba mi, mo gbadura, ma je ki n dojuti oruko re, bikose ki n ma se rere nigba gbogbo nibikibi ti mo ba lo.Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *