Say No To Covetousness

THE SEED
“Thou shalt not covet thy neighbor’s house, thou shalt not covet thy neighbor’s wife, nor his manservant, nor his maidservant, nor his ox, nor his ass, nor anything that is thy neighbor’s.” Exodus 20:17

As children of God, all things have been given to us from Heaven by His grace. These things are perfectly good and we must be satisfied with them. It is therefore a sin to have our eyes and minds on beautiful things that belongs to our neighbors at work, homes, Churches and anywhere we find ourselves. We do not have the same destiny neither do we share the same time and season to make it in life, so we have to patiently wait for our time and season for our destiny to shine. I pray, may our Glory come to play as we continue to abide Christ in Jesus Mighty Name. We should always be on our guard for life does not consist in the abundance of our possessions alone. Mind you, the Lord said the thought He has for us is good and not evil to give us an expected end. He is faithful and never fails. So, let us keep our fingers crossed, for our time for lifting and blessing is close to us than ever before but never covet your neighbor. God bless.

BIBLE READING: 2 Kings 5:22-27

PRAYER: Spirit of Covetousness that will take our beautiful tomorrow away from us will never come near us in Jesus name. Amen.

MASE SE OJUKOKORO

IRUGBIN NAA
Iwọ kò gbọdọ ṣojukokoro si ile ẹnikeji rẹ, iwọ kò gbọdọ ṣojukokoro si aya ẹnikeji rẹ, tabi iranṣẹkunrin re, tabi iranṣẹbinrin re, tabi akọmalu re, tabi kẹtẹkẹtẹ re, tabi ohunkohun ti iṣe ti ẹnikeji rẹ. Eksodu. 20:17.

Gẹgẹbi ọmọ Ọlọrun, ohun gbogbo ni a ti fi fun wa lati Ọrun nipasẹ ore-ọfẹ Rẹ. Awọn nkan wọnyi dara ni pipe a si gbọdọ je ki won te wa lorun. Nitorina o jẹ ẹṣẹ lati se ojukokoro si awon oun ti o dara ti o jẹ ti awọn arakunrinwa ni ibi iṣẹ, ile, Ile ijọsin ati nibikibi ti a ba ri ara wa. A ko ni ayanmọ kanna bẹni a ko pin akoko kanna ati igba lati ṣe rere laye, nitorinaa a ni lati fi suuru duro de akoko ati igba ayanmọ wa. Mo gbadura, je ki Ogo wa bu jade bi a ti n gbe nínú Jesu Kriti. A gbudo di Ara wa ni amure Tori pe aye ko le maa fun wa ni oun ti a ba Fe nigbagbogbo. Mo wipe, Ọlorun so pe ero ti O ni fun wa jẹ ohun ti o dara kii ṣe buburu lati fun wa ni opin ireti. Ó je olóòóto, kò sì kùnà láé. Nítorí náà, ẹ je kí a mura sile, nítorí àkókò igbéga àti ìbùkún wa ti sun mo ju ti tele lo. Ṣugbọn má ṣe ṣojukokoro ọmọnìkejì rẹ. Ọlọrun yoo bukun wa

BIBELI KIKA: IWE Oba Keji 5:22-27

ADURA: Emi Ojukokoro ti yoo gba ojo ola was kuro lowo wa ko ni sunmo wa laelae loruko Jesu. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *