Once Sold Out As Peanuts

THE SEED
“For you know that it was not with perishable things such as silver or gold that you were redeemed from the empty way of life handed down to you from your ancestors, but with the precious blood of Christ, a lamb without blemish or defect.” 1 Peter 1:18-19

As a Christian why are you acting and playing cheap? Why do you still place the cost of peanuts over your life after you have been bought with an inestimable price of the precious blood of Jesus? Why do you parade yourself in club houses to get drunk, being enveloped in flirting activities and using dubious ways to enrich your pocket all in the name of enjoyment and keeping up with friends? Once, the whole generation of man was sold out as peanuts, so cheap that it took only a few convincing lies from satan to make mother Eve disobedient to God’s instruction and for father Adam to fall for the persuasive and enticing words of his wife to become infected with the first evil pandemic called sin. Sin became contagious through their blood and infected everyone that is born of man. But glory be to God the Father, who in His infinite mercy sent us His only begotten son, Jesus Christ; to shed his precious blood in order to cleanse, purify and deliver us from eternal death. Brethren, after receiving this priceless gift of new life, is it wise to still go out of grace to be sold cheaply to Satan again? This will be the most unacceptable act towards God and our Lord Jesus.

BIBLE READING: 1 Peter 1:13-20
PRAYER: Lord help me to keep myself in your grace and never sell myself again to the hopeless world that you have redeemed me from. Amen

A FI IGBA KAN TAWA BI OHUN YEPERE
IRUGBIN NAA
“Nítorí eyin mo pé kì í ṣe àwọn ohun tí ó lè bàje bí fàdákà tàbí wúrà ni a fi rà yín padà kúrò nínú onà ìgbésí ayé asán tí a fi lé yín lowo láti odo àwọn baba ńlá yín, bí kò ṣe pelú eje iyebíye ti Kristi, odo-àgùntàn tí kò ní àbàwon tàbí àbùkù.” 1 Pétérù 1:18-19

Gege bí onígbàgbo, kí ló dé tí Iwo diye kekere le igbesi aye re leyìn ti a ti Ra o ni iyebiye pelú eje Jesu? Kini idi ti o fi n lo ile ijo Lati mu otin yo,ti Iwa agbere wo o lewu ti o si fi ọgbon arekereke ko Oro Jo nípase aye jíje atí ore Kiko? Ní ìgbà kan, gbogbo ìran ènìyàn ni a ta bi oun yepere tí kò won Debi pe iro kekere ni satani lo Lati tan Efa je, eyi ti o mu ki o se aigboran SI ofin Ọlorun, ti o si mu kí Ádámù bàbá wa ṣubú nípase Oro didun Efaa Aya re ti o si mu won ṣubu si Arun buburu ti ese. Ese sì tipase eje wọn ràn gbogbo àwọn tí a bí nípase omo ènìyàn. Sugbon ogo ni fun Olorun Baba, eniti o fi anu Re ailopin Jesu Kristi Omo bibi Re kansoso; láti ta eje re iyebiye ki o le fo wa, so wa di mimo àti láti gbà wá lowo ikú àìnípekun. Eyin ará, leyìn gbígba ebùn ìyè tuntun yìí tí kò níye lórí, nje o mu ọgbon Dani Lati kuro nínú ore-ofe yi Lati ta wa ni opo fun satani? Eyi yoo jẹ iṣe ti ko se itẹwogba julọ si Ọlọrun ati Jesu Oluwa wa.

BIBELI KIKA: 1 Pétérù 1:13-20
ADURA: Oluwa ran mi lọwọ lati pa ara mi mọ ninu oore-ọfẹ rẹ, kin n ma SI SE ta Ara mi leekan SI fun aye eyi ti o ti Rami pada kuro nínú re. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *