Hidden Believers

THE SEED
“I reserve seven thousand in Israel—all whose knees have not bowed down to Baal …” 1 Kings 19:18

Elijah was burned out. After confronting the prophets of Baal and winning a great victory, Elijah had thought Ahab’s pitiful kingdom would totter and fall. Not so. Instead, he had to run for his life. (See 1 Kings 18:16-19:9.) Elijah fled to Mount Horeb (Sinai), and there, standing before God, he cried out, “I am the only one left.” Really? God helped him do the math. The Lord had seven thousand people in Israel who had not bowed to Baal. Our near-sightedness can get in the way of seeing the far scope of God’s work in the world today. For example, did you know there are more than 12 million Christians in the Middle East. This is what they say to me: “We are forgotten by our brothers and sisters around the world.” How can we mobilize our resources of prayer and support to encourage their witness in the very part of the world where Christianity was born? Remember our brothers and sisters in the Middle East!

BIBLE READING: 1 KINGS 19:9-18

PRAYER: Lord, forgive our tendencies to ignore people we cannot see. Unite us by your Spirit with Christians in countries we might think are empty of the church’s presence. We know that you love them too. Amen.

AWON ONÍGBÀGBO TI O FARAPAMO

IRUGBIN NAA
“Mo pa egberun meje mo ni Ísreli—gbogbo awon ti i foribalẹ fun Baali…” 1 Ọba 19:18

Èlíjà Kun fun Ina. Leyìn tí ó dojú kọ àwọn wòlíì Báálì tí ó sì ṣegun ńlá, Èlíjà ti rò pé ìjọba Áhábù oníyọ̀onú yóò wó, yóò sì ṣubú. Bẹẹkọ. Kàkà beẹ̀, ó ní láti sá fún ẹ̀mí rẹ̀. (Wo 1 Ọba 18:16-19:9 .) Èlíjà sá lọ sí Òkè Hórébù (Sínáì), níbẹ̀ ló sì dúró níwájú Ọlorun, ó sì kígbe pé, “Èmi nìkan ṣoṣo ni ó ṣe kù.” Se tòóto ni? Ọlorun ràn án lowo láti ṣe ìṣirò. Olúwa je ki o mo wipe ẹgbẹ̀rún méje ènìyàn ní Ísírelì ni kò ti foribale fún Báálì. Airiran wa le Fa idena fun riri ise nla ti Ọlorun se nínú aye loni.. Bí àpẹẹrẹ, ṣé o mọ̀ pé àwọn Kristẹni tó lé ní mílíọ̀nù méjìlá ló wà ní Àárín Gbùngbùn Ìlà Oòrùn ayé. Ohun tí won sọ fún mi nìyí: “Àwọn arákùnrin àti arábìnrin wa kárí ayé ti gbàgbé wa.” Báwo la ṣe lè lo oun ini wa nipa ti Adura atí atilehin Lati le ro ijeri won lowo ni apa ibi ti a ti mu esin kristi jade wa? Rántí àwọn arákùnrin àti arábìnrin wa ni Ìlà Oòrùn!

BIBELI KIKA: 1 Àwọn Ọba 19:9-1

ADURA: Oluwa, dariji wa fun yiyera fun awon ti a ko le e ri. So wa Po ninu emi pelú awon onígbàgbo ti o wa ni orilẹ-ede ti a le ro pe ko si ile ijọsin. A mọ pe o nifẹ wọn pẹlu. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *