Dinner’s Ready!

THE SEED
“This man welcomes sinners and eats with them.” Luke 15:2

How do you connect with people who are different from you? One way is to sit together and share a meal. The Pharisees were shocked that Jesus had dinner with tax collectors, notorious for exploiting their own people, and with prostitutes and other sinners. Jesus’ accusers understood that he was taking a stand for community, especially with those who were despised and ostracized by the religious leaders. (See Luke 5:30-32.) I wonder whether an important part of our fellowship has been lost because we don’t regularly share meals with each other. Are you missing an element of Christian community that can be forged only around the dinner table? Is there someone you need to invite for a meal?

BIBLE READING: LUKE 15:1-7

PRAYER: Lord, may the fellowship of the Lord’s Supper spill over into our everyday relationships, especially with people who need to know you. Help us to practice the hospitality of sharing meals, for your sake. Amen.

OUNJE ALE TI SETAN

IRUGBIN NAA
“Okunrin yi gba elese lalejo, o si baa jeun.” Luku 15:2

Bawo ni o ṣe n ni ìbáṣepo pẹlu awọn eniyan ti o yatọ si ọ? Oun kan ni lati joko pọ jẹun. O je oun ìyàlenu fun awon farisi wipe Jesu ba agbowo ode jẹun, eni ti o je eni buburu ti o n Yan awon eniyan re je, bee si ni pelú awon alagbere atí awon elese miran. Awon olufisun Jesu mo wipe ife Ara ilu lo n se, paapa julo fun awon ti atifoju pare atí awon ti a ti yo legbe nípase olori elesin. (Wo Lúùkù 5:30-32 .) O máa ń je ìyàlenu pe ohun pàtàkì kan nínú ìjosin wa ni a ti sonu nitori wipe, a kì í n jẹun pẹ̀lú ara wa déédéé. Njẹ iwo padanu oun kan nínú ìbáṣepo Kristiani eyi ti a le mu bo sipo nípase ounjẹ jije? Ṣe ẹnikan wa ti o nilo lati pe fun ounjẹ?

BIBELI KIKA: LÚÙKÙ 15:1-7

ADURA: Olúwa, je kí ìdàpọ̀ Oúnjẹ Ale Olúwa Dara Po mo ìbáṣepọ̀ wa lojoojúmo, paapa julo pẹ̀lú àwọn ènìyàn tí won nílò láti mọ̀. Ran wa lọwọ lati le maa se alejò sise jije ounjẹ papo, nitori tirẹ. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *