DON’T PROCRASTINATE
THE SEED
“A lazy life is an empty life, but ‘early to rise’ gets the job done” Proverbs 12: 27 MSG
Don’t postpone that action you want to take till tomorrow. Take action now. Procrastination is not good. Don’t delay in taking that action. Don’t postpone what you can do today till tomorrow. Procrastination has reduced many potential great men and women from the place of greatness and honour. Procrastination has stopped millions from attaining the peak that heaven destined for them.
What have you been pushing till tomorrow? What is your excuse? Bury those excuses today and take action. Doors of favour will not open until you step out and take necessary action.
BIBLE READING: Proverbs 12: 24-28
PRAYER: Heavenly Father, help me not to postpone what I am supposed to do today to tomorrow so as not to postpone my moving forward in Jesus’ name.
MASE FI DOLA
IRUGBIN NAA
“Igbe aye ole n sofo, sugbon eni ti o tete ji ni n se ise naa.” Owe 12:27
Mase fi ohun ti o fe se ni dola, gbe igbese loni, fifi ohun eni dola kii se ohun ti o dara. Mase jafara lati gbe igbese ni loni. Mase fi ohun ti o le se loni dola. Fifi ohun eni dola ti so opolopo awon ti o ye ki won di okunrin tabi obinrin nla di eni yepere, o ti dena aimoye eniyan lona ati de ibi giga ti Olorun ti ko mo won.
Kinni ohun ti o ti nfi dola? Kini awawi re? gbe awon aroye wonni ti ki o si gbe igbese. Awon ilekun ojurere ko le si, ayafi bi o ba jade ki o si gbe igbese ti o ye.
BIBELI KIKA: Owe 12: 24-28
ADURA: Baba wa Orun, ranmi lowo kin mase fi ohun ti o ye kin se loni dola, kin ma baa fi itesiwaju mi dola ni oruko Jesu. Amin