THE SEED
Now unto him that is able to do exceeding abundantly above all that we ask or think, according to the power that worketh in us,” Ephesians 3:20
This scripture doesn’t just say God can do it. He said God can do exceeding abundantly above all that we ask or think. God is Ably Able in His Ability. Our words cannot fully Express what we know and Feel. God is able to keep his word—if you get a promise from God hold on to it—it may tarry in it’s coming, but it will come—once he says it, it is completed—no worry, no fear, no doubt should enter in—that is the only thing that keeps people from entering into the promises of God. All his promises are yes and amen.. His word will not return void, it will accomplish what it sets out to do. As we go through life living it out day by day we ultimately will face many troubles, hardships, trials and tribulations. What ever it is, remember God is able to do exceedingly abundantly above all that we ask or think and that comes from the power of the Holy Spirit that lives in us. *God is Able* – That must be our first Response to anything in life
BIBLE READING: Ephesians 3
PRAYER: Father Lord I know you are able to do all things in my life and my family, let your will come to pass in Jesus name
ỌLỌ́RUN KUN OJU OSUWON NIGBA GBOGBO
IRUGBIN NAA
“Njẹ fun ẹniti o le ṣe lọpọlọpọ ju gbogbo eyiti a bère tabi ti a rò lọ, gẹgẹ bi agbara ti nṣiṣẹ ninu wa,” Efesu 3:20
Iwe-mimọ yii ko sọ pe Ọlọrun le ṣe. O sọ pe Ọlọrun le ṣe lọpọlọpọ ju gbogbo ohun ti a beere tabi ronu lọ. Ọlorun Alagbara ninu Agbara Re. Awọn ọrọ wa ko le ṣe afihan ohun ti a mọ tàbí imolara ni kikun. Ọlọ́run lè pa oro re mọ́. Ti ẹ bá gba ìlérí kan láti odo Ọlọ́run, dii mu sinsin. O le pe, ṣùgbọ́n yóò se niwon ígbà tí ó ti sọ ọ́. Kò sí àníyàn, kò sí ìberù, kò sí iyèméjì to gbudọ wọ inu Okan re. Eleyi nikan ni ohun ti o di eniyan lowo lati ma ni imuse ileri Ọlọrun. Gbogbo ileri re ni beni ati Amin.. Oro re ki yio pada sofo, yio se ohun ti o pinnu lati se. Bí a ṣe ń gbe igbesi ayé wa lójoojúmọ́, a máa dojú kọ opolọpo wàhálà, ìnira, idánwò àti ìpọ́njú. Ohunkohun ti o ba jẹ, ranti pe Ọlọrun ni agbara lati ṣe lọpọlọpọ ju gbogbo ohun ti a beere tabi ti a ro ati ti o wa lati agbara ti Ẹmí Mimọ ti o ngbe inu wa. Ọlọrun ni Agbara – Iyẹn gbọdọ jẹ Idahun akọkọ si ohunkohun ninu igbesi aye
BIBELI KIKA: Éfésù 3
ADURA: Baba Oluwa Mo mọ pe o le ṣe ohun gbogbo ni igbesi aye mi ati idile mi, jẹ ki ifẹ rẹ ṣẹ ni orukọ Jesu