The Lord Roars

THE SEED
“The LORD also shall roar out of Zion, and utter his voice from Jerusalem; and the heavens and the earth shall shake: but the LORD will be the hope of his people, and the strength of the children of Israel.” Joel 3:16

God unleash His majestic roar in a new and fresh way, to capture your attention and get you to change. His is a holy roar. The roar of love ends up on the cross when Jesus said, “It is finished!!!” All of sin is paid for! There is no more need for a sacrifice. That roar from the cross is still echoing through the ages, and through out the entire universe. Do you hear it? Have you grown cold to it’s power. The Lord will roar from Zion and thunder from Jerusalem; the earth and the sky will tremble. But the Lord will be a refuge for his people, a stronghold for the people of Israel. Jesus Christ wants to roar into your life. It’s a holy roar, it’s a loving roar, and it’s a winning roar. How will you respond the roar of the Lion standing before you: with apathy or indifference? The Lion of Judah is worthy…He is able to give you and me life! His roar of love can warm the coldest hearts…and revive the most apathetic spirit. His roar says that He is passionate for you! Are you passionate and sold out for the Lion of Judah, the Lord Jesus Christ. His is a loving roar…He wants to roar into your life! He Roars so you would take sin seriously and conform to His holiness…He Roars so you would take His love seriously and love others. He Roars so you would realize when all is said and done Jesus Christ wins and reigns and you would have the courage to join the battle.

BIBLE READING: Isaiah 29:6, 31:4, Hosea 11:9-11, Amos 3:3-8

PRAYER: Lion Of Judah roar in my life and silence the noise of sin standing against my life

OLUWA KE RAMURAMU

IRUGBIN NAA
“Oluwa pẹlu yio bu ramúramù lati Sioni wá, yio si fo ohùn re jade lati Jerusalemu; ọrun oun aye yio si mì: ṣugbọn Oluwa yio ṣe ireti awọn ẹniyan re, ati agbara awọn ọmọ Israeli.” Jóẹ́lì 3:16

Ọlọ́run tú ariwo ọlá ńlá re síle ní onà tuntun, láti pe àkiyèsí rẹ ki o si mu ọ yí padà. Ariwo mímọ́ ni tire. Ariwo ifẹ pari lori agbelebu nigbati Jesu sọ pe, “O ti pari !!!” Gbogbo gbese ẹṣẹ ni o ti san fun wa! Ko si iwulo fun ẹbọ riru kan mọ. Igbe yi lati ori agbelebu si n fohun lati Iran de iran ni gbogbo agbaye. Ṣe iwo gbọ o? Njẹ o ti di tutu si agbara rẹ? Oluwa yio hó lati Sioni wá, ati ãrá lati Jerusalemu wá; aye ati sanma yio warìri. Ṣùgbọ́n Olúwa yóò jẹ́ ibi ìsádi fún àwọn ènìyàn re, ààbò fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. Jesu Kristi fe kigbe sinu aye re. O jẹ ariwo mimọ, o jẹ ariwo ifẹ, ati pe o jẹ ariwo ti o bori. Bawo ni iwọ yoo ṣe dahun ariwo kiniun ti o duro niwaju rẹ: pẹlu aibikita? Kiniun Juda je eni eye. O le fun iwọ ati emi ni iye. Ariwo ifẹ rẹ le mu ọkan ti o tutu julo gbona, ki o si ji Okan aibikita. Ariwo rẹ sọ pe O ni itara fun ọ! Ṣe o ni itara fun Kiniun Juda, Oluwa Jesu Kristi. Ariwo re jẹ ariwo ifẹ. O fẹ kigbe sinu igbesi aye rẹ! Ó ń ké ramúramù kí o lè sa fun ese kí o sì jẹ́ mímọ́. Ó ń ké ramúramù kí o lè mú ìfẹ́ re ni okunkun dun kí o sì nífẹ́ àwọn ẹlòmíràn. O kigbe ki o ba le mọ nigbati o ba so Gbogbo re tan, ti Jesu Kristi ṣegun ti o si joba, nigba naa ni Iwo yio ni igboya lati darapo mo Lati jagun.

BIBELI KIKA: Isaiah 29:6, 31:4, Hosea 11:9-11, Amosi 3:3-8

ADURA: Kìnnìún Júdà ké ramúramù nínú ayé mi kí o sì pa ariwo ese tí ó dúró lòdì sí ayé mi mọ́

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *