THE STORY OF JESUS

THE SEED

“Yet a little while, and the world seeth me no more; but ye see me: because I live, ye shall live also.” John 14:19

The story of Jesus is not a story at all, it’s the truth, The truth is that Jesus has paid it all. He was crucified on a cross and laid in a tomb, but death was not His master and neither does death need be our master, Why?. Because He lives, and because He lives, in my heart, there rings a melody, a melody that I can face to tomorrow, a melody of hope in hopeless times, a melody of strength when I am weak, a melody that offers life, because I know my Saviour lives, and because I know Jesus paid it all, and because I know He Lives and because of the melody that is ringing in my heart, I will go in all the world, I will proclaim that Jesus is alive, I will tell of His goodness and His grace, I will tell of how He has changed my life, but most importantly I will tell that one day, He will Coming again. The story of Jesus is so wonderful to me, that it just can’t be spoken with words, it must be sung, So amazing is the Lord Jesus.

BIBLE READING: John 14

PRAYER: Hallelujah Christ lives in  me

 ITAN JESU

IRUGBIN NAA

“Nigba die si, aye ki o si ri mi mo, sugbon eyin yio ri mi, nitoriti emi wa laye, eyin o wa laye pelu.” John 14 :19

Itan Jesu kiise itan rara, otito ni. Otito ni wipe Jesu ti san gbogbo re. A kan mo igi , A si gbe sinu iboji, sugbon iku kiise oga re, be gege ni kiise oga tiwa naa, kilode? Nitori O nbe laaye. Nitori pe o nbe laaye, okan mi nko orin, orin wipe mo le dojuko ola. Orin ireti ni awon asiko ti  ko si ireti, orin fun agbara nigba ti mo se ailera, orin ti o mu iye wa , nitori wipe mo mo wipe olugbala mi nbe laaye, ati nitori wipe mo mo wipe Jesu ti san gbogbo re. Tori mo mo wipe o nbe laaye, ati nitori orin ti nbe ninu okan mi, ngo lo si gbogbo aye, ngo polongo pe Jesu nbe laaye, ngo so nipa oore re ati ore-ofe, ngo so nipa bi o se yi aye mi pada.

Pataki julo, ngo so nipa ipadabo re. itan Jesu je iyanu fun mi, a o le so tan ninu oro, a ni lati ko lorin. Jesu Oluwa je iyanu.

BIBELI KIKA: John 14

ADURA: Alleluya, Kristi ngbe inu mi

 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *