POWER OF PROPHECY

THE SEED
“This charge I commit unto thee, son Timothy, according to the prophecies which went before on thee, that thou by them mightest war a good warfare;” 1 Timothy 1:18
The power of prophecy enables us to get through difficult times. Prophecy will take us from Problem to Promise. God knows all things and only He is able to predict the future with amazing accuracy. We have questions – what is going to happen next? Are we going to make it, will it get better? The Power of Prophecy over problems enables us to live beyond the questions and struggles of today. Prophetic words may come through a sermon. They may come through someone who is a spiritual authority in our life—perhaps a parent or a truly anointed prophet. Or they may come through God’s written Word. Prophecy is a word from God about ourselves or family’s future. Grab hold of the prophecies of God’s Word over your life and begin to proclaim them against the enemy. Go to war with the prophecies you’ve been given. When you do, the power of God will dwell in your life full of hope and expectations.

BIBLE READING: 1 Timothy 1

PRAYER: Let your prophecy concerning my life come to pass in Jesus name Amen

 

 AGBARA ISOTELE

IRUGBIN NAA

“Ase yi ni mo pa fun o, Timoteu omo mi, gege bi asotele wonni ti o ti saaju lori re, pe nipa won, ki iwo ki o le maa ja ogun rere.” 1 Timoteu 1:18

Agbara asotele ma nran wa lowo lati la akoko lile koja. Asotele ma mu wa lati inus isoro lo sinu ileri. Olorun mo oun gbogbo, oun nikan ni o si le so oun ti yio sele ni ojo iwaju ti ki yi o si tase.

A ni ibeere wipe kini yio sele?, se ao ri se? Se yio dara ? agbara asotele lori isoro nran wa lowo lati bori awon ibeere ati ilakaka ode oni. Oro asotele le wa nipa iwaasu, o le wa nipase eni ti o je alase ninu emi lori aye wa, boya obi wa tabi wooli otito, o si le wa nipa oro Olorun ti a ko sile.

Asotele je oro lati odo Olorun nipa ojo iwaju wa ati idile wa. Gba asotele oro Olorun mu lori aye re ki o si maa jewo won . lo si oju ogun pelu asotele ti a ti fun o. nigba ti o ba se eyi, agbara Olorun yio buyo ninu aye re pelu ireti.

BIBELI KIKA: 1 Timotiu 1

ADURA: Jeki asotele re fun aye mi wa si imuse ni oruko Jesu , Amen.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *