A Grateful Heart

THE SEED

“O give thanks unto the Lord; call upon His Name, make known His deeds among the people. Sing unto Him, sing psalms unto Him, talk ye of all His wondrous works.” Psalm 105:1-2 (KJV)

To whom much is given much is expected, whosoever that does not know how well to appreciate gifts and blessings from God is not ready to receive another one, the person is nothing but an ingrate. God loved us so much He did not want us to lack anything good, He said ‘’if ye then being evil know how to give good gifts unto your children, how much more shall your Father which is in Heaven give good things to them that ask Him’’. That is why His thought towards us is always good and never evil to give us an expected end. So by the time you key into all His promises through prayers and supplications and He harkens to your voice giving you in abundance all what you asked for, grant you solutions to all your problems and tribulations, fight and win your battles for you, God indeed deserves your praises, songs and sharing of your testimonies to show case the existence of the power of the Almighty, appreciate Him, reverence His Sovereignty. He will definitely do more for you, even those things you did not request for. You will be surprised to have them. God dwells in the praise of His people. You are being encouraged today to always have a grateful heart. God is everything in everything, after Him no one else. He is a Mighty God the Great I AM. Halleluiah!!

PRAYER
Lord I pray for the Spirit of thanksgiving and a grateful heart, let it rest upon me in Jesus Name. Amen
BIBLE READINGS: Psalm 103:1-22

OKAN TI O MOORE

“Efi ope fun Oluwa, e pe oruko re, e fi ise re han ninu awon enia. E korin sii, e ko orin mimo sii, e maa soro ise iyanu re gbogbo.” Orin Dafidi 105 :1-2

Eniti a ba se lore, o ye ko dupe, enikeni ti ko ba mo bi a ti n dupe lowo Olorun fun awon ebun ati ibukun re, ko se tan lati gbo omiran. Alaimoore ni iru eniyan bee. Olorun feran wa to bee ge ti ko fe ki a se alaini ohun rere, O wipe “bi eyin tinse eniyan buburu ba mo bi a tii fi ebun ohun rere fun omo, melomelo baba yin ti mbe ni Orun a maa fi fun awon ti o beere lowo re.” idi niyi ti ero re si wa fi je rere ti kii si se ti ibi ati lati fun wa ni opin ti o dara. Nigba ti o ba di awon ileri re wonyi mu nipa adura ati ebe ati pe o n gbo igbe re, a si maa fi ohun gbogbo ti o beere fun ni ekunrere, a maa fun o ni ona abayo kuro ninu isoro ati idamu re. a maa ja ajasegun fun o, Nitooto, gbogbo ope ati iyin, orin re ni o to si Olorun ati siso awon eri ti o maa n fi agbara Olorun han, dupe lowo re, teriba fun isakoso re. Yio tunbo maa se pupo si ninu aye re, ati awon ohun ti o ko tile beere fun. A gba o niyanju loni pe ki o ni emi imoore. Olorun ni ohun gbogbo ninu ohun gbogbo, leyin re ko si elomiran. Ohun ni Olorun alagbara, atobiju, emi ni ti n je emi ni. Halleluya!

ADURA
Oluwa, mo gbadura fun Emi ti ndupe ati okan to moore, je ki o ba lemi ni oruko Jesu. Amin.
BIBELI KIKA: Orin Dafidi 103:1-22

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *