A WHOLE HEART FOR GOD
THE SEED
“And he did that which was right in the sight of the Lord, but not with a perfect heart.” — 2 Chronicles 25:2 KJV
Amaziah did what was right in God’s sight
but not with a perfect heart. His actions were
good, but his devotion was not complete. Serving God with a divided heart limits the flow of His blessings. Hezekiah, on the other hand, served with full devotion, and his results were different. True worship requires total commitment, not half measures. God desires a heart that loves, serves, and honours Him without reservation.
BIBLE READINGS: 2 Chronicles 29:1–5
PRAYER: Oh Lord, give me a heart to love
and serve You wholeheartedly. Amen.
ỌKÀN TÍ Ó PÉ FÚN ỌLỌ́ RUN
IRUGBIN NAA
” Ó ṣe ohun tí ó dára lójú Olúwa, ṣùgbọ́n kì í ṣe tọkàntọkàn” 2 KRONIKA 25:2
Amasiah ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú Ọlọrun, ṣugbọn kì í ṣe pẹlu ọkàn pípé. Awọn iṣe rẹ dara, ṣugbọn ifọkansin rẹ ko kun ojú òṣùwòṇ . Sísin Ọlọ́run pẹ̀lú ọkàn tí ko dúró dede le dín àwọn ìbùkún Rẹ̀ kù. Hesekiah, ni idakeji sìn pẹ̀lú ìfọkànsìn kíkún, àbájáde ìsìn rẹ̀ sì yàtọ̀. Ìsìn tootọ pè fún ìfọkànsìn to kújúwòn, ki ìṣe afi apá kan ara ṣé. Ọlọ́ run fẹ́ ọkàn tíó nífẹ̀, tíó n sìn n, tíó sì ń bọlá fún un láìsí ikùn sinú.
BIBELI KIKA: 2 Kíróníkà 29:1–5.
ADURA: Oluwa, fun mi ni ọkàn ti o nifẹ ati lati sin Ọ pẹlu gbogbo ọkàn. Amin.